2Face Idibia

Innocent Ujah Idibia (tí a bí sí ìlú Jos, ìpínlẹ̀ Plateau State, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ 2Baba, jẹ́ olórin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, akọrin sílẹ̀, agbọ́rin jáde àti onísẹ́ àdáni.

Ní oṣù keje Odun 2014, ó yan 2face Idibia gẹ́gẹ́ bí orúkọ ìtàgé rẹ̀. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórin ilẹ̀ Áfíríkà tó ń kọ orin Afro pop tí ó lọ́lá jùlọ tí ó sì gbayì. Ó ti lé lógún ọdún tí 2Baba tí ń kọrin tí ó sì ń dánilárayá ó sì jẹ́ ògbóǹtarìgì síbẹ̀.

2Baba
2Baba attending the album release party for his sixth studio album, The Ascension.
2Baba attending the album release party for his sixth studio album, The Ascension.
Background information
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi2face Idibia
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kẹ̀sán 1975 (1975-09-18) (ọmọ ọdún 48)
Jos, Plateau, Nàìjíríà
Occupation(s)
  • Olórin
  • Olùkọ́ orin
  • Olùgbórin jáde
  • Oníṣòwò àdáni ní
Instruments
  • Vocals
  • vocal percussion
Years active1994–present
Labels
  • Hypertek Digital
Associated acts

Ó tún jẹ́ onínúdídùn ọlọ́rẹ.

Ìgbésí ayé àti ètò-èkó rẹ̀

A bí Innocent Idibia sí ìlú Jos, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ Idoma ní apá gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó lọ sí Mount Saint Gabriel's Secondary School ní ìlú Makurdi, ìpínlẹ̀ Benue. Ó tún lọ sí Institute of Management & Technology (IMT) ní ìpínlẹ̀ Enugu níbi tí ó ti gboyè National Diploma nínú Business administration and management. Nígbà tí ó wà ní IMT, ó máa ń kọrin níbi ayẹyẹ àti àwọn ilé-ìwé gíga bíi University of Nigeria Enugu State University of Science & Technology. Kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó kúrò nilé-ìwé ó sì gbájúmọ́ orin kíkọ. Ní ọdún 1996, ó yan "2face" gẹ́gẹ́ bíi orúkọ ìtàgé rẹ̀.

Ní ọdún 2016, ó yí orúkọ ìtàgé rẹ̀ sí 2Baba.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

JosPlateau State

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÈbuÒrò àyálò YorùbáKarim MassimovNumerianAtomÁpártáìdìAmẹ́ríkàRamesses 6kNordrhein-WestfalenÌsọdipúpọ̀ZÈdè LátìnìEdmund Husserl8 NovemberÁténìList of language regulatorsNọ́mbàJet LiOrin-ìyìn ÒmìniraSáúdí ArábíàPhasianidaeÈdè YorùbáKàsínò.ehKievLimpopoLebanonÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáOṣù Kínní 19Màríà (ìyá Jésù)Saint PetersburgPtolemy 5k EpiphanesJodie FosterN'DjamenaSchwerinẸṣinÌsirò Statistiki.smHerta MüllerJorge Tadeo LozanoÀtòjọ àwọn akọ̀ròyìn ilẹ̀ NàìjíríàÌpínlẹ̀ Bọ̀rnóIlẹ̀ ọbalúayé BrítánììDíámọ̀ndìProgressive Graphics File9 DecemberEl SalfadorTallinnÒjòPelu AwofesoAkanlo-edeIrunSaint Kitts àti NevisJuho Kusti PaasikiviNomba atomuWélsìFolashade AdefisayoIlú-ọba Ọ̀yọ́Àkójọ àmì-ìdámọ̀ àwon apilẹ̀sẹ̀KryptonKrakówPsusennes 1kVientianeGeraldine PageIrak🡆 More