Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá ti a mo si Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, UK tabi Britani jẹ́ orílẹ̀-èdè ní Europe.
Nínú bodè rẹ̀ ni a ti rí erékùsù Brítánì Olókìkí, apá ìlàoòrùn-àríwá erékùsù Irẹlandi àti ọ̀pọ̀ àwọn erékùsù kékéèké. Irẹlandi Apáàríwá nìkan ni apá Ilẹ̀ọba Ìsọ̀kan tó ní bodè mọ́ oríilẹ̀ pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Irẹlandi.
Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándì Apáàríwá United Kingdom of Great Britain and Northern Ireland[1] | |
---|---|
Orin ìyìn: "God Save the King"[3] | |
Ibùdó ilẹ̀ Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan (dark green) – on the European continent (light green & dark grey) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | London |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | English[4] |
Lílò regional languages | Welsh, Irish, Ulster Scots, Scots, Scottish Gaelic, Cornish[5] |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2001) | 92.1% White, 4.00% South Asian, 2.00% Black, 1.20% Mixed Race, 0.80% East Asian and Other |
Orúkọ aráàlú | British, Briton |
Ìjọba | Parliamentary system and Constitutional monarchy |
• Monarch | Charles III |
• Prime Minister | Rishi Sunak |
Aṣòfin | Parliament |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | House of Lords |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | House of Commons |
Formation | |
• Acts of Union | 1 May 1707 |
• Act of Union | 1 January 1801 |
• Anglo-Irish Treaty | 12 April 1922 |
Ìtóbi | |
• Total | 244,820 km2 (94,530 sq mi) (79th) |
• Omi (%) | 1.34 |
Alábùgbé | |
• mid-2006 estimate | 60,587,300 (22nd) |
• 2001 census | 58,789,194 |
• Ìdìmọ́ra | 246/km2 (637.1/sq mi) (48th) |
GDP (PPP) | 2006 estimate |
• Total | US$2.270 trillion (6th) |
• Per capita | US$37,328 (13th) |
GDP (nominal) | 2007 estimate |
• Total | $2.772 trillion (5th) |
• Per capita | US$45,845 (9th) |
Gini (2005) | 34 Error: Invalid Gini value |
HDI (2005) | ▲ 0.946 Error: Invalid HDI value · 16th |
Owóníná | Pound sterling (£) (GBP) |
Ibi àkókò | UTC+0 (GMT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (BST) |
Àmì tẹlifóònù | 44 |
Internet TLD | .uk [6] |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.