Ẹgbẹ́ òṣèlú jẹ́ ẹgbẹ́ tí àwọn òṣèlú tí ìmọ̀, òye àti èròǹgbà jọra dá sílẹ̀ láti díje dupò òṣèlú ní orílẹ̀ èdè tí wọ́n bá lẹ́tọ̀ọ́ rẹ̀ lábẹ́ òfin.
Ìfojúsùn gbogbo ẹgbẹ́ òṣèlú ni láti jẹ àwọn ipò òṣèlú tí ó bá ṣí sílẹ̀ lórílẹ̀ èdè wọn.
Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ti Independent National Electoral Commission|INEC, àpapọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ ókànléláàdọ́rùn-ún (91).
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ẹgbẹ́ òṣèlú, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.