Òkè Olúmọ ni òkè kan tí nó wà ní ilẹ̀ Ẹ̀gbá ìlú Abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn ní apá ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.
Òkè Olúmọ jẹ́ ibìsálà fún àwọn ará Abẹ́òkúta ní àsìkò ogun abẹ́lé ní àsìkò 19th century. Wọ́n sì ń bọ òkè náà gẹ́gẹ́ bí Òrìṣà tí wọ́n sì ń bọọ́ pẹ̀lú oríṣríṣi ẹbọ.
Òkè Olúmọ jẹ́ ọ̀kan pàtàkì nínú àwọn òkè gbajúmọ̀ tí àwọn ènìyàn ma ń lọ bẹ̀wò láti gbafẹ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Òkè Olúmọ, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.