Wurld

Sadiq Onifade, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí WurlD, jẹ́ Olórin àti Akọ-Orin Nàìjíríà.

Wọ́n bi ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà, WurlD padà lọ sí Atlanta, Georgia láti lépa ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndírí rẹ̀ àti láti tẹ orin jáde. Ó pe bátànì orin tirẹ̀ ní ẹlẹtiro-fúíṣọ̀nì. Ó kọ EP rẹ̀ àkọ́kọ́ tó pè ní Evolution ní ọdún 2013.

WurlD
Image of Sadiq Onifade
Image of Sadiq Onifade
Background information
Orúkọ àbísọSadiq Onifade
Ọjọ́ìbíLagos, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
  • record producer
InstrumentsVocals
Years active2012–present
LabelsWEAREGVDS
Associated acts
  • Mario
  • Major Lazer
  • Walshy Fire
  • Gromee
  • B.o.B
  • Akon
  • Timbaland
  • Sir Felix
  • Scotty ATL
  • Shizzi
  • Trinidad James
  • Sarz
Websitewurldmusic.com

Ìgbẹ́sí ayé rẹ̀ lórí orin rẹ̀

Ní ìgbẹ̀yìn ọdún 2012, WurlD kọ orin tuntun , "Beyond Our Dreams" lára EP rẹ̀ àkọ́kọ́ tó pè ní Evolution, ní àsìkò súmà ọdún 2013. Tó jẹ́ ìgbà kan náà pẹ̀lú SESAC tí ó ṣe òde ráńpẹ́ ní ilé-isé wọn ní Atlanta fún EP WurlD tó bọ lọ́nà nígbà náà Evolution EP. Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún 2013, WurlD wà ní ilé–iṣẹ́ tí wọ́n tí gbórin jáde pẹ̀lú Mario, tí wọn kọ orin fún álíbọ̀mù Olórin náà tó ń bọ̀ lọ́nà. Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, vídíò orin kejì fún álíbọ̀mù Evolution tí ó ń jẹ́, "Alive", tó jẹ́ dídarí láti ọwọ́ Black Shield Entertainment producer Hood Beatz, jáde fún ìgbà àkọ́kọ́ lórí MTV.

Àwọn EP
Title Album details
Evolution
  • Released: 20 August 2013
  • Label: Wurld Music Entertainment
  • Formats: Digital Download
Love is Contagious
  • Released: 28 March 2019
  • Label: Universal Music Nigeria
  • Formats: Digital Download
I love girls with Trobul (Wurld & Sarz)
  • Released: 8 November 2019
  • Label: WEAREGVDS/1789
  • Formats: Digital Download
Afrosoul
  • Released: May 15, 2020
  • Label: WEAREGVDS/IMMENSUM MUSIC
  • Formats: Digital Download


Àwọn orin
Year Title Chart positions Album
US UK POL
2012 "Beyond Our Dreams" Evolution (EP)
2013 "Alive"
"All Night" (Gromee song)
2015 "Follow You" (Gromee song) 11 Chapter One
"Who Do You Love" (Gromee song)
"Summer Yours"
2016 "Show You Off" (ft. Shizzi & Walshy Fire)
2017 "All Night 2017" (Gromee song) Chapter One
"Mother's Prayer"
"All I Need"
2018 "Trobul" I LOVE GIRLS WITH TROBUL

(EP)


Àwọn orin tó ti fara hàn
Year Title Other performer(s) Album
2013 "Beautiful Girls" BK Brasco TBA
2015 "Let You Go" Leriq The Lost Sounds
Netflix n Chill B.O.B & London Jae
2016 "Fantasies" B.O.B & Scotty ATL The Cooligan
"Let It Rain" B.O.B & Scotty ATL Live & Direct
Better Days Sir Felix
$till Aware Trinidad James & Scotty ATL
2017 I Know B.O.B Ether
Fake Friends B.O.B
2019 Sweet in the middle Davido & Naira Marley & Zlatan Ibile A Good Time


Àwọn oyè

Year Event Prize Recipient Result Ref
2019 The Headies Best Vocal Performance (Male) "Wishes and Butterflies" Gbàá
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="duhoc-yo no table-no2"|Wọ́n pèé
Hip Hop World Revelation style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="duhoc-yo no table-no2"|Wọ́n pèé

Ìtọ́kaṣí

Tags:

Wurld Ìgbẹ́sí ayé rẹ̀ lórí orin rẹ̀Wurld Ìtọ́kaṣíWurld

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

8 MayParagúáìTógòMẹ́rkúríù (pálánẹ́tì)Santos AcostaJohn LewisFẹlá KútìJẹ́mánìSCaliforniaỌdẹErékùṣùSalawa Abeniaue2713 OctoberÀwọn sáyẹ́nsì àwùjọEhoroÌlàoòrùn Jẹ́mánìWashington, D.C.Èdè TháíMaria Najjuma30 MayLítíréṣọ̀Igbesi aye mi ninu igbo ti Awọn ẹmi (aramada)Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tìÈṣùJoaquín Francisco Pacheco y Gutiérrez-CalderónWikipediaPsamtik 1kAlifabeeti OduduwaGoogleMariam CoulibalyÈdè Lárúbáwá30 April1 OctoberIowaCalabarỌjọ́ ÀìkúOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Eugenio MontaleGbólóhùn YorùbáÌmúrìnGúúsù-Ìlàòrùn Ásíà2022Arunachal Pradesh10 FebruaryJean DujardinAdeniran OgunsanyaBomadiZambiaPópù Benedict 6kÈdè iṣẹ́ọbaPennsylvania21 JuneSenior Advocate of NigeriaLogicOrúkọ ìdíléPierre NkurunzizaÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Kàlẹ́ndà Gregory23 MayOregonFránsì🡆 More