Walter Raleigh A bi i ni 1552.
O ku ni 1618. Soja omo ile Geesi ni o si maa n rin irinajo pupo. Oun ni o mu taba wa si ile Geesi ti o si mu 'potato' wa si Ireland. Oun ati Sir Humphrey Gilbert (ti o je half-brother) ni won jo ja ni ile Amerika. O tun ja fun ile Geesi ni Ireland. Iwe History of the World ti o ko ko pari re titi ti o fi ku. Won pa a ni nitori pe ko pa ofin mo.
Sir Walter Raleigh | |
---|---|
Iṣẹ́ | Writer, poet, soldier, courtier, explorer |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Walter Raleigh, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.