Tajudeen Oyèwọlé tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Abìjà ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹwá , ọdún 1957.Jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá àgbéléwò, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ó sábà ma ń kópa nínú eré sinimá gẹ́gẹ́ bí ògbójú babaláwo àti oníṣègùn tó gbóná tí ó sì ma ń fi agbára rẹ̀ gba àwọn ènìyàn sílẹ̀ nínú eré.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Tajudeen Oyèwọlé (Abìjà), which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.