Sam Smith

Samuel Frederick Smith (tí a bí ní 19 May 1992) jẹ́ akọrin àti aṣẹ̀dá orin ọmọ orílè-èdè England.

Lẹ́yìn tí ó di olókìkí ní oṣù kẹwàá ọdún 2012 nípasẹ̀ ìṣàfihàn rẹ̀ nínú orin àdákọ tí àkọ́lé rè ń jẹ́ " Latch ", èyí tó ṣipò kọkànlá lórí atọ́ka Singles UK. Wọ́n sì padà ṣàfihàn orin "Naughty Boy" tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "La La La" tó ṣịpò kìíní lóṣù karùn-ún, ọdún 2013. Ní oṣù kejìlá ọdún 2013, wọ́n yan Smith fún àmì-ẹ̀yẹ Brit Critics Choice Award, ti ọdún 2014, ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ méjèèjì.

Sam Smith
Sam Smith
Smith performing at the 2015 Lollapalooza
Ọjọ́ìbíSamuel Frederick Smith
19 Oṣù Kàrún 1992 (1992-05-19) (ọmọ ọdún 31)
London, England
Iṣẹ́
  • Singer
  • songwriter
Ìgbà iṣẹ́2008–present
AwardsFull list
Musical career
Irú orin
Instruments
  • Vocals
Labels
  • Capitol
Websitesamsmithworld.com

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

KánádàÀwọn ọmọ UkraníàJames D. WatsonÈdè JavaMàkáùMario BooysenLudwig van BeethovenSocratesMọ́ṣálásíZimbabweẸyẹWokingÌwé PsalmuSwídìnAlbert EinsteinYorùbáÌjídìde FránsìMadagásíkàÈdè YorùbáJamaica11 AprilOlógbòKinshasaMùhọ́mádùPópù SymmachusẸ̀sìn IslamJohn Fitzgerald KennedyWerner HeisenbergMichael CaineAderounmu AdejumokeSally FieldSwítsàlandìDenis IstominHerbert KroemerÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáRáràUNICEFFrédéric ChopinSpaceXRene UysMẹ́tálọ́ìdìPeléTheodore RooseveltYousaf Raza GillaniÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ IndonésíàAgbègbè àkókòHelmut KohlEartha KittIndonésíàDavid CameronKizz DanielÒrò àyálò YorùbáÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunArméníàÀjọ àwọn Orílẹ̀-èdèJúpítérìÌkólẹ̀jọ Saint MartinIlẹ̀ọbalúayé Rómù ApáìlàoòrùnIbn KhaldunÁbídíAli NuhuNorman MailerParisiBarack ObamaOrúkọ YorùbáFederated States of MicronesiaÈdè EsperantoBuenos Aires🡆 More