Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica (Èdè Látìnì fún Àwọn Ìpilẹ̀sẹ̀ Matimátíìkì fún Imọ̀-òye Adánidá, Mathematical Principles of Natural Philosophy ní èdè Gẹ̀ẹ́sì), tí wọ́n tún tọ́ka sí bíi Principia ( /prɪnˈsɪpiə,_prɪnˈkɪpiə/ prinkípíà), ni ìwé apá mẹ́ta tí Isaac Newton kọ ní èdè Látìnì, tí wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀jáde ní 5 July ọdún 1687.
Lẹ́yìn tí Newton ṣe àtúnṣe sí àtẹ̀jáde àkọ́kọ́ ìwé yìí, ó tún tún tẹ̀ jáde ní ọdún 1713 àti ọdún 1726. Principia ṣe àkọsílẹ̀ àwọn òfin ìmúrìn Newton, tí wón jẹ́ ìpìlẹ̀ ìṣiṣẹ́-ẹ̀rọ ògbólògbó; òfin ìfàmọ́ra gbogbo únkan Newton; àtí ìwájáde àwọn òfin ìmúrìn plánẹ́tì Kepler (tí Kepler kọ́kọ́ fi first obtained ọgbọ́n ìrírí wá jáde).
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Philosophiæ Naturalis Principia Mathematica, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.