Michael Clarke Duncan (December 10, 1957 – September 3, 2012) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà.
Ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ókó nínú eré The Green Mile (1999) tí wọ́n sì fa orúkọ rẹ̀ sílẹ fún àmì ẹ̀yẹ Akádẹ́mì.. Ní ọdún 2009, ó jọ̀wọ́ ẹran jíjẹ tí ó sì jádé fún ìpolongo PETA, tí ó ń jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ̀ ìlera tí ó rọ̀ mọ́ ewé jíjẹ.
Wiki Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Michael Clarke Duncan |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Michael Clarke Duncan, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.