Kim Fields: Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Kim Victoria Fields (ọjọ́ìbí May 12, 1969) ni òṣeré àti olúdarí ètò tẹlifísàn ará Amẹ́ríkà.

Fields gbajúmọ̀ fún ìseré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Dorothy "Tootie" Ramsey nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn NBC The Facts of Life (1979–1988), àti gẹ́gẹ́ bíi Regine Hunter nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn Fox, Living Single (1993–1998). Fields ni ọmọ Chip Fields tí òhun náà jẹ̀ òṣeré àti olùdarí, àti ẹ̀gbọ́n Alexis Fields.

Kim Fields
Kim Fields: Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Fields in 2019
Ọjọ́ìbíKim Victoria Fields
Oṣù Kàrún 12, 1969 (1969-05-12) (ọmọ ọdún 54)
New York City, New York, U.S.
Orúkọ mírànKim Fields Freeman
Ẹ̀kọ́Pepperdine University
Iṣẹ́Actress, director
Ìgbà iṣẹ́1977–present
Gbajúmọ̀ fúnThe Facts of Life, Living Single
Olólùfẹ́
Johnathon Franklin Freeman (m. 1995–2001)

Christopher Morgan (m. 2007)
Àwọn ọmọ2
Parent(s)Chip Fields (mother)
Àwọn olùbátanAlexis Fields (sister)

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

JamaicaWiki CommonsÒrò àyálò YorùbáÌṣeọ̀rọ̀àwùjọÀtòjọ àwọn oúnjẹ Ilẹ̀ Adúláwọ̀AwonÀwọn Erékùṣù KánárìIbn KhaldunNọ́rwèyJésùInstagramÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunÒkunHonoluluOṣù KẹtaÀwọn ọmọ Áfíríkà Amẹ́ríkàRichard FeynmanTurks and Caicos IslandsCouncil of EuropeAtlantaManhattanAyò ọlọ́pọ́nHawaiiTanin KraivixienWerner HeisenbergPortland Trail BlazersWokingViktor YanukovychOrílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ ṢáínàÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáSonyNicaraguaNatalie PortmanÈdè PólándìÌwà ÀjẹbánuÌwọòrùn ÁfíríkàBọ́ọ̀lù-alápẹ̀rẹ̀Pópù Jòhánù 4kṢàngóBoris JohnsonGbólóhùn YorùbáTsílèOlógbòIlẹ̀ ọbalúayéBavariaÀjákálẹ̀ àrùn káàkiriayé èrànkòrónà ọdún 2019 2020.nlFrank SinatraAnandi Gopal JoshiColumbus, OhioC SharpÌtànBillie EilishMuhammad AliÈdè PọtogíJohn Maynard KeynesAbdullah ilẹ̀ Sáúdí ArábíàJosephine BakerKikan Jesu mo igi agbelebuPópù Leo 10kDesmond TutuBob MarleyRahmon Ade BelloMichael Jackson2021Cleopatra VIIOrílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ MakẹdóníàItálíàÈdè EsperantoFrench PolynesiaPatrick Leahy🡆 More