Khalifa bin Zayed bin Sultan Al Nahyan to je Sheikh (Lárúbáwá: خليفة بن زايد بن سلطان آل نهيان), (ojoibi 1948), ti won unpe ni Sheikh Khalifa ni Aare orile-ede awon Emirati Arabu Ajepiparapo (UAE) ati emiri ilu Abu Dhabi lowolowo.
O bo si ipo mejeji na ni 3 November 2004, nigba to dipo baba re Zayed bin Sultan Al Nahyan, to ku ni ojo kan seyin ojo na.
Khalifa bin Zayed Al Nahyan | |
---|---|
2nd President of the United Arab Emirates | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 3 November 2004 | |
Alákóso Àgbà | Maktoum bin Rashid Al Maktoum (2004-06) Mohammed bin Rashid Al Maktoum (2006-) |
Vice President | Maktoum bin Rashid Al Maktoum (2004-06) Mohammed bin Rashid Al Maktoum (2006-) |
Asíwájú | Zayed bin Sultan Al Nahyan |
2nd Deputy Prime Minister of the United Arab Emirates | |
In office 1973–1977 | |
Ààrẹ | Zayed bin Sultan Al Nahyan |
Alákóso Àgbà | Maktoum bin Rashid Al Maktoum |
Asíwájú | Hamdan bin Rashid Al Maktoum |
Arọ́pò | Hamdan bin Mohammed Al Nahyan |
Crown Prince of Abu Dhabi | |
In office 1969 – 3 November 2004 | |
Monarch | Zayed bin Sultan Al Nahyan |
Arọ́pò | Mohammed bin Zayed Al Nahyan |
Ruler's Representative in the Eastern Region of Abu Dhabi | |
In office 1966–1967 | |
Monarch | Zayed bin Sultan Al Nahyan |
Asíwájú | Zayed bin Sultan Al Nahyan |
Arọ́pò | Tahnoun bin Mohammed Al Nahyan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1948 (ọmọ ọdún 75–76) Al Ain, Abu Dhabi, Trucial States |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Shamsa bint Suhail Al Mazrouei Daughter of Tahnoun bin Mohammed Al Nahyan |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Khalifa bin Zayed Al Nahyan, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.