Arthur Ashe

Arthur Robert Ashe, Jr.(July 10, 1943 – February 6, 1993) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfasẹ́ gbá tenis, tí wọ́n bí, tó dàgb̀a, sí Richmond, Virginia.

Nípa iṣẹ́ bọ́ọ̀lù rẹ̀, ó jáwé olúborí tí ́ó sì gba ife-ẹ̀yẹ Grand Slam mẹ́ta, èyí tí ó sò di ìkan nínú àwọn tó dára jùlọ nínú tenis ní Amẹ́ríkà. Ashe, tí ó jẹ́ ọmọ Afrika Ameríkà, tún jẹ́ riranti fun akitiyan re fun ilosiwaju awujo.

Arthur Ashe
Arthur Ashe
Arthur Ashe
Orílẹ̀-èdèUSA USA
IbùgbéPetersburg, Virginia
Ìga6 ft 1 in (1.85 m)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1969
Ìgbà tó fẹ̀yìntì1980
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed; one-handed backhand
Ẹ̀bùn owóUS$2,584,909
Ilé àwọn Akọni1985 (member page)
Ẹnìkan
Iye ìdíje818-260
Iye ife-ẹ̀yẹ33
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (1969)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (1970)
Open FránsìQF (1970, 1971)
WimbledonW (1975)
Open Amẹ́ríkàW (1968)
Ẹniméjì
Iye ìdíje315–173
Iye ife-ẹ̀yẹ18
Last updated on: July 24, 2007.

Itokasi

Tags:

African AmericanTennisUnited States of AmericaVirginia

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Chika IkeISO 14644-4Robin WilliamsIsraelJanusz WojciechowskiMongolia (country)Iṣẹ́ Àgbẹ̀Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàỌjọ́ 18 Oṣù KẹtaÀkójọ àwọn orílẹ̀-èdèÀtòjọ àwọn oúnjẹ Ilẹ̀ Adúláwọ̀WikisourceMorgan FreemanTsẹ́kì OlómìniraÈdè JavaBelarusISO/IEC 14443Jerome Isaac FriedmanPọ́nnaSnoop Dogg.nuNaìjírìàC++Ere idarayaIbùdó Òfurufú AkáríayéD. O. FagunwaRichard NixonTallinnÍsráẹ́lìMediaWikiUnited Arab EmiratesẸranko afọmúbọ́mọAlice BradyOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàOgun Àgbáyé KìíníISO 14644Orílẹ̀ èdè AmericaNikarágúàÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Délé GiwaInstagramIléKarachiAmẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lùÀkàyé(9981) 1995 BS3SvalbardAstanaRọ́síàWikinewsCristiano RonaldoNigerian People's PartyẸ̀gẹ́MonacoChris RockMiguel MiramónÀwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan ilẹ̀ Amẹ́ríkàOpeyemi AyeolaISO 5776ISO 31ISO 8601Àgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn OlóróAyo AdesanyaMicrosoft🡆 More