Open Australia je ikan ninu awon idije Grand Slam merin to uwaye ninu ere-idaraya alagbase Tenis.
O unwaye lodoodun ni Australia labe ase Tennis Australia, teletele tounje Egbe Ajose Tenis Australia (Lawn Tennis Association of Australia, LTAA) beesini idije akoko re waye lori papa isere kriket ni Melbourne ni 1905. Loni won unpe ibe ni Albert Reserve Tennis Centre.
Open Austrálíà Australian Open | ||
---|---|---|
Official website | ||
Ibùdó | Melbourne Australia | |
Pápá | Melbourne Park | |
Orí pápá | Plexicushion Prestige | |
Men's draw | 128S / 128Q / 64D | |
Women's draw | 128S / 96Q / 64D | |
Ẹ̀bùn owó | A$23,140,000 (2009) | |
Grand Slam | ||
Open Australia koko bere bi Idije-eye Australasia (Australasian Championships) ko to wa di Idije-eye Australia (Australian Championships), ni 1927 to si di Open Australia (Australian Open) ni 1969.. Open Australia di sisi sile, eyun open, fun awon osise agba tenis ni odun 1969, odun kan leyin ti awon idije Grand Slam meta yioku ti di open fun awon osise agba tenis.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Open Austrálíà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.