Karl Theodor Jaspers (February 23, 1883 – February 26, 1969) je asewosan-emin ati amoye ara Jemani to ko ipa gidi lori oro-olorun odeoni.
Leyin to ko eko nipa bi a ti n se iwosan-emin, Jaspers boju de iwadi imoye, o si tiraka lati wa sistemu imoye tuntun. O je gbigba bi akede iseoniwalaaye ni Jemani, botilejepe ko faramo pipe be.
Karl Theodor Jaspers | |
---|---|
Karl Jaspers | |
Orúkọ | Karl Theodor Jaspers |
Ìbí | Oldenburg, Grand Duchy of Oldenburg, Germany | Oṣù Kejì 23, 1883
Aláìsí | February 26, 1969 Basel, Switzerland | (ọmọ ọdún 86)
Ìgbà | 20th-century philosophy |
Agbègbè | Western Philosophy |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Existentialism, Neo-Kantianism |
Ìjẹlógún gangan | Psychiatry, Theology, Philosophy of History |
Àròwá pàtàkì | Axial Age, coined the term Existenzphilosophie, Dasein and Existenz |
Ipa látọ̀dọ̀ | |
Ìpa lórí Heidegger, Sartre, Camus, Paul Ricoeur, William A. Earle, Hans-Georg Gadamer, Hannah Arendt, Lacan |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Karl Jaspers, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.