Fati Lami Abubakar

Fati Lami Abubakar tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 (12 April 1951) jẹ́ Adájọ́ àgbà Ìpínlẹ̀ Niger, Obìnrin àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà àti Aya Ààrẹ-àná, Abdulsalami Abubakar lọ́dún 1998 sí 1999.

Ó di Adájọ́ àgbà ní Ìpínlẹ̀ Niger lọ́dún 2013 sí 2016.

Hon

Fatima Lami Abubakar
Adájọ́ àgbà fún Ìpínlẹ̀ Niger
In office
March 2013 – April 2016
AsíwájúHon. Justice Jibrin Ndajiwo
Obìnrin àkọ́kọ́ fún Nàìjíríà àti Aya Ààrẹ-àná lọ́dún 1998 sí 1999
In office
June 1998 – May 1999
ÀàrẹAbdulsalami Abubakar
AsíwájúMaryam Abacha
Arọ́pòStella Obasanjo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Fatima Lami

12 Oṣù Kẹrin 1951 (1951-04-12) (ọmọ ọdún 73)
Minna, Nigeria
(Àwọn) olólùfẹ́Abdulsalami Abubakar
Àwọn ọmọSix

Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀

Wọ́n bí Fati lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 1951 ní ìlú Minna, ní [[Ìpínlẹ̀ Niger] [lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.Ó kàwé ni Queen Elizabeth School ní [[Ilorin], ní Ìpínlẹ̀ Kwara. Bẹ́ẹ̀ náà, ó kàwé ní Federal Government College, ní Ìpínlẹ̀ Sokoto, àti ní Obafemi Awolowo University, Ilé Ifẹ̀, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin, bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè ọ̀mọ̀wẹ́ nínú ìmọ̀ Philosophy. Bákan náà, Fati kàwé gboyè ní 'Nigeria Law School'.

Ìgbésí ayé rẹ̀ lọ́tọ̀

Fati Lami fẹ́ Àárẹ̀ àná, Abdulsalami Abubakar, wọn sìn bí ọmọ mẹ́fà fún ara wọn.

Ayé rẹ̀

Abubakar ti fẹ́ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nígbà kan rí, Abdulsalami Abubakar, ẹni tí ó bí ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Fati Lami Abubakar Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀Fati Lami Abubakar Ìgbésí ayé rẹ̀ lọ́tọ̀Fati Lami Abubakar Ayé rẹ̀Fati Lami Abubakar Àwọn ìtọ́kasíFati Lami AbubakarAbdulsalami AbubakarNàìjíríàÌpínlẹ̀ Niger

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

TunisiaMóldófàFrederica WilsonA tribe called JudahOba Saheed Ademola ElegushiFacebook(6065) 1987 OCÀdánidáMax HorkheimerRita DominicIlà kíkọ nílẹ̀ YorùbáGrover ClevelandÌlú BeninWasiu Alabi PasumaOmoni OboliSalvatore Quasimodo19 SeptemberIléMary SoronadiDGírámà YorùbáRobert HofstadterTòmátòAisha AbdulraheemEewo ninu awon igbagbo YorubaMarseilleInternet Movie DatabaseÍsráẹ́lìOkoẹrúMarcel ProustÌpínlẹ̀ ÍmòMichigan22 DecemberMons pubisIlẹ̀gẹ̀ẹ́sìÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáBrie LarsonUniform Resource LocatorRita WilliamsÌnáwóOregonÌjímèrèKàlẹ́ndà Gregoryaue27Michael JordanFiennaISO 15897Lizzy jayISO 31-1KòkòròJẹ́mánìGenevaBratislavaRáràAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ BindawaOṣù Kẹ̀sán1 NovemberÀsìkòVincent van GoghISO 13490EarthWiki CommonsBerneAndré Frédéric CournandLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Ajah, Lagos🡆 More