Abobaku jẹ fiimu kukuru ti won se ni 2010 nipasẹ Femi Odugbemi ati oludari ni Niji Akannii.
Fiimu naa gba ami eye fiimu to ta yo ni nu awon fiimu to kukuuru ju ni igba gede Zuma Film Festival ni odun 2010 ati ami eye fun eso ti o dara julọ ni ibi ayeye ’’Africa Movie Academy Awards’’ ele kefa iru e ti o waye ni ọjọ kewa osu Kẹrin ọdun 2010 ni Ile-iṣẹ Aṣa Gloryland ni agbegbe Yenagoa, ni Ipinle Bayelsa, orilede Niajiria..
Abobaku | |
---|---|
Adarí | Niji Akanni |
Olùgbékalẹ̀ | Femi Odugbemi |
Òǹkọ̀wé | Dapo Olawale |
Ìyàwòrán sinimá | Niji Akanni |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | DVWORX Studio |
Déètì àgbéjáde | 2010 |
Àkókò | 35 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba and subtitled in English |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Abobaku, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.