Ọláídé Ọláògún

Ọláídé Ọláògún tí a tún mọ̀ síỌláídé Omololá Ọláògún Emmanuel tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 1986,(July 9, 1986) jẹ́ Òṣèrébìnrin, Afẹ́wà-ṣojú àti Atọ́kùn ètò ọmọ Nàìjíríà.

Ó ti fìgbà kan jẹ́ Afẹ́wà-ṣojú oṣẹ Lux

Ọláídé Ọláògún
Ọláídé Ọláògún
Ọjọ́ìbíJuly 9, 1986
Lagos
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànỌláídé Ọláògún Emmanuel
Ẹ̀kọ́African Church Model College, University of Lagos
Iṣẹ́Òṣèrébìnrin, Afẹ́wà-ṣojú àti Atọ́kùn ètò
Gbajúmọ̀ fúnSinimá àgbéléwò
Olólùfẹ́Babatúndé Ọ̀jọrá Emmanuel
Àwọn ọmọỌmọ kan

Ìgbésí-ayé rẹ̀

Wọ́n bí Ọláídé Ọláògún ní ìlú Èkó lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 1986. Ó kàwé ní African Church Model College. Bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè nínú èdè Òyìnbó ní University of Lagos.

Ọláídé Ọláògún 
The new faces of Lux in 2007

Ó di gbajúmọ̀ òṣèré ní Nàìjíríà àti Ghana nígbà tí ó kópa nínú eré kan tí Wale Adenuga gbé jáde lórí tẹlifíṣàn, ti àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ "Soul Sisters" and she was also in the Yoruba series Super Story.

Lọ́dún 2007, ó gba ipò Genevieve Nnaji gẹ́gẹ́ bí afoge-ṣojú nínú ìpolówó-ọjà ọṣẹ Lux and continued in this role until 2009. Bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ afoge-ṣojú ilé iṣẹ́ aṣerunlóge, Diva hair extension, Fuman juice àti Ilé-ìfowópamọ́ United Bank for Africa (UBA).

Ìgbésí-ayé ara rẹ̀

Ọláídé fẹ́ Babátúndé Ọ̀jọrá Emmanuel lọ́kọ lọ́dún 2015 wọ́n sìn bímọ kan péré fún ara wọn lọ́dún 2016. She was married to Babatunde Ojora in 2019.

Àtẹ àṣàyàn àwọn iṣẹ́ rẹ̀

Ọdún Sinimá Ẹ̀dá-ìtàn Àkíyèsí
2005 Omoye Racheal
2005 A new Song Juliet
2006 Elulu Tafajo Tayo
2006 Lion of Mogun Série télé
2006 Odu
2006 Iyawo Afoju
2007 Everything it takes
2007 Elerin Eye Mopelola
2008 Tinsel
2008 Eleburu Ike
2009 Atehinbo
2009 The Perfect Church
2010 Hands of a Stranger Tokunbo Babs Oshodi
2010 The Promise Ego
2011 Obi Eni
2011 Valentine Rose
2013 Memuna Gbagi

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Ọláídé Ọláògún Ìgbésí-ayé rẹ̀Ọláídé Ọláògún Ìgbésí-ayé ara rẹ̀Ọláídé Ọláògún Àtẹ àṣàyàn àwọn iṣẹ́ rẹ̀Ọláídé Ọláògún Àwọn ìtọ́kasíỌláídé ỌláògúnNàìjíríà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Rosalyn Sussman YalowKhanyi MbauWOwo siseWiki CommonsDNAKinshasaÌnàkíMaya AngelouJames Clerk MaxwellColumbus, OhioỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)3 JuneBùkólá Adéẹyọ̀Jorge Pacheco ArecoFẹ́mi GbàjàbíàmílàAllan McLeod CormackIkejaMársìBitcoinÌpínlẹ̀ Ògùn5 DecemberA trip to jamaicaSILKDonald J. Cram(225275) 6890 P-LẸ̀yà ara ÈnìyanLariNúmérì preferredÈdè Gẹ̀ẹ́sìJay-ZPaul D. BoyerOwe YorubaSátúrnùIke EkweremaduLutetiumGbọ̀ngàn Òfurufú KennedyGuinea-BissauElizabeth BlackburnPashtoOhioWindows Media AudioJemima OsundeJohn Hasbrouck Van VleckNiameyTracy AustinBeatrice StraightLinuxPresident of the United States of AmericaOjúewé Àkọ́kọ́Lọ́kọ́jaÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ EstóníàGeneral Exchange FormatKim BasingerTobi BakreÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàNẹ́ptúnùRọ́síàÀsìá ilẹ̀ Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan2023Antonio GramsciFranklin PierceTemilade Openiyi1341 EdméeMáàdámidófòArab29 October20 JulyRahama SadauKọ̀mpútàGùyánà FránsìPolitician🡆 More