Ìtúká Onítítànyindin

Ìtúká onítítànyindin tabi ítuka titanyindin tabi ituka radioaktifu ni igbese nibi ti nukleu atomu kan ti atomu ti ko ni iduro lese pofo okun-inu nipa yiyojade awon alaratintinni toun je sisodi ioni (iranka ijeonisisodiioni|).

Awon orisirisi iru ituka titanyindin lowa. Ituka, tabi ipofo okun-inu, unsele nigbati atomu kan to ni iru nukleu kan, to unje radionuklidi obi, yirapada di atomu to ni nukleu kan ni ipoaye to yato, tabi to di nukleu oto to ni iye proton ati neutron oto. Eyi to wu ninu awon yi ni o unje nuklidi omo. Ninu awon ituka miran obi ati omo je elimenti kemika otooto, nitori eyi igbese ituka fa iyirapada nukleu wa (ida atomu elimenti tuntun).

Ìtúká Onítítànyindin
Ìtúká álfà jẹ́ àpẹrẹ kan irú is one example type of ìtúká títànyindin, nibi ti nukleu atomu kan ti tu alfa alaratintinni kan sita, bi bayi to yirapada (tabi 'tuka') di atomu to din ni nomba akojo 4 ati to din ni nomba atomu 2. Orisi iru ituka miran lo tun se e se.


Itokasi

Tags:

Atomic nucleusChemical elementProton

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Levi P. MortonÀàlàDagobert 1kRudolph ilẹ̀ BurgundyAdo-EkitiOrin blues17 DecemberÀwọn ará Jẹ́mánìPhiladelphiaOgun Abẹ́lé Amẹ́ríkà1 JulyDaniel BernoulliGerman languageNílòOduduwaMartin Heidegger1 AprilHawaiiÀgbọ̀rínVincent van GoghWerner ArberConnecticutIrakÌṣèlúSaarlandGuamPolitics of BeninMaputoEré Òṣùpá28 NovemberJẹ́mánìMikaẹli GọrbatsẹfMikhail BakuninPotassiumSan FranciscoÀlgéríàÈdè Pẹ́rsíàSalvador AllendeKatarLÌmọ́lẹ̀Herbert MacaulayẸṣinTurkeyJudi DenchÒjòNFemi D AmelePepsiIdi Amin DadaWiki CommonsÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Mọfọ́lọ́jì èdè YorùbáOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àpapọ̀ Sófìẹ̀tì Sósíálístì Rọ́síàLouis 12k ilẹ̀ FránsìÀndórà10 MarchDhakaGuatemala CityOjúewé Àkọ́kọ́Fọ́tòyíyàBohriomuCasablancaISO 3166Ilé ọba àwọn Nẹ́dálándìKúbàBòlífíàAlfred TarskiTPtolemy 5k EpiphanesTibetHuman Rights Watch🡆 More