Ìpínlẹ̀ Èkó: Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà

Ìpínlẹ̀ Èkó jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríài.

láàárin àwọn ìpńilẹ̀ mẹ́rìndìnlógójì náà, ó pọ̀ níye ó sì kéré ní ààyè. Ó sopọ̀ mọ́ gúúsù nípasẹ̀ àwọn ìgbèríko Benin àti sí ìwọ̀-oòrùn nípasẹ̀ ààlà òkèèrè pẹ̀lu Ìlu Benin, Ìpínlẹ̀ Èkó ń pín àwọn ààlà pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Ogun sí ìlà-oòrùn àti àríwá ní èyí tí ó mu jé ìpńilẹ̀ kan ṣoṣo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó pín ààlà pẹ̀lú ìpínlẹ̀ kan péré. Orúkọ fún ìlú Èkó — Ìlú tí ó pọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ adúláwọ̀ — wọ́n dá ìpínlẹ̀ náà látara agbègbè Ìwọ̀ Oòrùn tí ó sì jẹ́ olú-ìlú tẹ́lèrí ní ọjọ́ kẹ́tadínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún, ọdún 1967.

Ìpínlẹ̀ Èkó
Ìpínlẹ̀ Èkó: Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà
Flag of Lagos State
Flag
Location of Lagos State in Nigeria
Location of Lagos State in Nigeria
Orílẹ̀-èdèÌpínlẹ̀ Èkó: Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà Nàìjíríà
Ọjọ́ ìdásílẹ̀May 27, 1967
OlùìlúIkeja
Government
 • GómìnàBabájídé Olúṣọlá Sanwó-Olú (APC)
 • Àwọn alàgbà
  • Munirudeen Muse
  • Ọlámilékan Adéọlá
  • Olúrẹ̀mí Tinúbú
 • Àwọn aṣojúÀkójọ
Area
 • Total3,475.1 km2 (1,341.7 sq mi)
Population
 (2006 Census)
 • Total9,013,534
 • Density2,600/km2 (6,700/sq mi)
GIO (PPP)
 • Ọdún2007
 • Total$33.68 billion
 • Per capita$3,649
Time zoneUTC+01 (WAT)
ISO 3166 codeNG-LA
Websitelagosstate.gov.ng

Gégẹ́ bí ìtọ́ka agbègbè, Ìpínlẹ̀ Èkó jé ilẹ̀ omi tí ìdá-mẹ́rin rẹ̀ dín ní díẹ̀ kúnfún òṣà, itọ́ àti àwọn odò. Èyí tí ó fẹ̀ jù nínú àwọn omi wọ̀nyí ni ọ̀sà Èkó àti Lekki nínú ìpínlẹ̀ náà pẹ̀lú odò Ogun àti Osun tí ó ń sàn wọnú wọn. Àwọn omi yòó kù jẹ́ itọ́ tí ó ń sàn kiri ìpínlẹ̀ náà tí wọ́n sì jẹ́ ọ̀nà ìrìnàjò pàtàkì fún àwọn èèyàn àti àwọn ọjà. Offshore, ìpínlẹ̀ yìí bákan náà ṣàkónú àwọn onírúnrú ohun ọ̀gbìn, ẹranko àti ẹranmi gẹ́gẹ́ bí ẹjá ṣe wà náà ni àwọn ẹranmi ilẹ̀ adúláwọ̀ àti àwọn ọ̀ọ̀nì.

Ìpínlẹ̀ Èkó ti jé ibùgbé fún ọdún tó ti pẹ́ nípasẹ̀ àwon ọ̀wọ́ onírúnrú ẹ̀yà onílùú, nípàtàkì awọn ọmọ Yoruba ni wọ́n ń gbé káàkiri ìpínlẹ̀ náà àmọ́ àwọn èèyan Ewe àti Ogu náà ń gbé ibi tí o nasẹ̀ lápá ìwọ̀ oòrùn.

Gẹ́gẹ́ bí àbáyọrí síṣí lọ láti orílẹ̀ èdè kan sí òmíràn láti bíi ọ̀rúndún sẹ́yìn, ìpínlẹ̀ Èkó pẹ̀lú ti ní èrò tó pọ̀ tí wọn kìí ṣe àwọn ọ̀wọ́ ẹ̀yà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú Edo, Fulani, Hausa, Igbo, Ijaw, Ibibio, àti èèyàn Nupe láàárin àwọn ọ̀wọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà yòókù. Àwọn ọ̀wọ́ mìíràn wa látìta tí wọn wá láti àwọn ìlú tí ó pín ààlà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pèlú Saro (Sierra Leonean) àti Amaro (Brazilian) gẹ́gẹ́ bí àwọn ọ̀wọ́ tí wọn ṣẹ̀ wá tí wọ́n kó lẹru tẹ́lẹ̀rị́ tí wọ́n padà sílẹ̀ adúláwọ̀ ní àwọn ọdún 1800 pẹ̀lú àwọn àwùjọ àárín ìlà-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ti wà ti pẹ́ (pàápàá Syrian àti Lebanese orílẹ̀-èdè Nàìjíríà) pẹ̀lú di èrò ní apákan gbòógì ní ìpínlẹ̀ Èkó pẹ̀lú àwọn tí wọ́n ṣí wá láìpẹ́ láti ìlu Benin, China, Ghana, India, Togo, àti United Kingdom.

Babájídé Sanwóolú ni gómìnà ìpínlè Èkó.



Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

en:Benin Republicen:Bight of Beninen:Nigeria

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ÀríwáNọ́rwèyOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìUnited Nations3254 BusDélé Mọ́mọ́dùÁljẹ́brà onígbọrọIléÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáJohn MiltonSpéìnC++MáàdámidófòPakístànÒṣèlúÈdè HébérùAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Abẹ́òkútaInáISO 10206Aloma Mariam MukhtarSantos AcostaLinda IkejiZSaint HelenaÌlú-ọba Brítánì OlókìkíSaxonyISO 31-10Èdè EsperantoÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-202014 November7 October16 February23 AugustÁntíllès àwọn Nẹ́dálándìBeirutÈdè YorùbáTheodor Heuss22 MarchRonald ColmanBostonRáràQuincy Jones1633 ChimaySudan1168 BrandiaEarthZincÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàTunde IdiagbonKóstá RikàỌrọ orúkọHesseÀsìáFrancisco FrancoBaltimoreIlẹ̀ọba Aṣọ̀kan Brítánì Olókìkí àti Írẹ́lándìRẹ̀mí ÀlùkòItan ijapa ati igbinHypertextÀtòjọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ RùwándàÀdánidáSQL.geKọ́nsónántì èdè YorùbáOgun🡆 More