Ìpínlẹ̀ Delta: Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà

Ipinle Delta je ipinle kan nini awon Ipinle ni orile-ede Naijiria.

Ìpínlẹ̀ Delta
State nickname: The Big Heart
Location
Location of Delta State in Nigeria
Statistics
Governor
(List)
Emmanuel Uduaghan (PDP)
Date Created 27 August 1991
Capital Asaba
Area 17,698 km²
Ranked 23rd
Population
1991 Census
2005 estimate
Ranked 9th
2,570,181
4,710,214
ISO 3166-2 NG-DE

Ìpínlè Delta wà ní apa Guusu Nàìjíríà. Adá Ìpínlè Delta kalè ní ojo ketadinlogbon, osu kejo, odun 1991(27, August 1991) ní abe isejoba Gen. Ibrahim Babangida . Olú-ìlú Ìpínlè Delta ní Asaba bí otile jepe ìlú Warri ìkan aje/oja kale sí jù. Àwon èyà tí opoju ní Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri . Ìpinlè Delta ní Ìjoba Agbegbe Ibile marundinlogbon(25) Arakunrin Emmanuel Uduaaghan ti fi igba je gomina ipinle delta ri labe asia egbe oselu PDP. .Oruko gomina ipinle delta lowolowo bayii ni arakunrin Ifeanyi Okowa

Awon Ìjoba Agbegbe Ìbílè ti Delta

• Aniocha North • Aniocha South • Bomadi • Burutu • Ethiope South • Ethiope east • Ika North East • Ika South • Isoko North • Isoko South • Ndokwa east • Ndokwa west • Okpe • Oshimili North • Oshimili South • Patani • Sapele • Udu • Ughelli North • Ughelli South • Ukwuani • Uvwie • Warri North • Warri South • Warri South West

Olokiki eniyan

  • Kefee, olori obinrin ati ko-orin Naijiria
  • Sunny Ofehe, oluselu ati ajafitafita
  • Isaiah Ogedegbe, elesin aguntan ati oluso buloogi



Itokasi

Tags:

Awon Ipinle NaijiriaNaijiriaNàìjíríà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Sesi Oluwaseun WhinganIsaiah WashingtonBẹ̀lárùs23 AugustAbidjanÀkúrẹ́SARS-CoV-2.lrHorsepowerNkiru OkosiemeYukréìnVictoria, Ṣèíhẹ́lẹ́sìOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́Kenneth ArrowNamibiaPyongyangỌrọ orúkọÀsà ilà kíkọ ní ilé Yorùbá.bzIndonésíàIrinTẹ́lískópù27 JuneÒgún LákáayéOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàChinedu IkediezeCharlize TheronÈdè TúrkìXÍslándìLa RéunionDoris SimeonSeye Kehinde.afAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ido-OsiTẹlifísànAbraham LincolnWikipediaShehu Abdul RahmanHamburgJaime LusinchiISO 128Pópù Jòhánù 14kBerenice IV of EgyptAmiri BarakaBọ́ọ̀lù-alápẹ̀rẹ̀Bello Hayatu GwarzoOmiÀwọn Ìdíje Òlímpíkì2009Ìmọ̀ Ẹ̀rọÒjòAgbonLagos State Ministry of Economic Planning and BudgetCaliforniaÈdèCharlemagneÒrùnLinda IkejiFrans Eemil Sillanpää.blProlog🡆 More