Awon Adugbo ile Ghana je titungbajo ni 1988/1989 lati mu ise ijoba sunmo awon aralu ati lati koju iwabaje to gbale larin awon onibise.
itundajo awon opin 1980 pipinlabe awon Agbegbe ile Ghana si adugbo 110, nibi ti awon ile-igbimo ibile adugbo kookan ti le dojuko isoro imojuto ibile ti won. Ni 2006, awon adugbo 28 tuntun je didasile eyi mu apapo iye awon adugbo de 138. Ni February 2008, awon adugbo miran tun je didasile lati mu iye apapo de 170 ni Ghana.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Àwọn àdúgbò ilẹ̀ Ghánà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.