Henry Olusegun Adeola Samuel (ọjọ́ìbí 19 February 1963), tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ bíi Seal, ni akọrin àti olùdá-orin ará Brítánì.
Àwo orin rẹ̀ ti tà tó 20 millionu àwo orin káàkiri àgbáyé, pẹ̀lú orin rẹ̀, "Crazy", tó gbéjáde ní ọdún 1991; àti "Kiss from a Rose", tó gbéjáde ní ọdún 1994.
Seal | |||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Seal in Sydney, 2012 | |||||||||||
Background information | |||||||||||
Orúkọ àbísọ | Henry Olusegun Adeola Samuel | ||||||||||
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Sealhenry Samuel | ||||||||||
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kejì 1963 Paddington, London, England | ||||||||||
Irú orin | |||||||||||
Occupation(s) |
| ||||||||||
Years active | 1987–present | ||||||||||
Labels |
| ||||||||||
Associated acts |
| ||||||||||
|
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Seal, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.