Orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle ni ilẹ̀ aládàáni kan tí ó únlo àwọn òfin onímàle fún ìjọba, ó sì yàtọ̀ sí ilẹ̀ọba onímàle.
Fún lílò ní orúkọ, àwọn orílẹ̀-èdè mẹ́rin ló jẹ́ orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle. Àwọn wọ̀nyí ni Afghanistan, Iran, Mauritania and Pakistan. Pakistan ló kọ́kọ́ lo orúkọ yìí ní 1956 lábẹ́ òfin-ìbágbepọ̀; Mauritania bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó ní 28 November 1958; Iran bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó lẹ́yìn Ìjídìde àwọn ará Ìránì 1979 tó gbàjọba lọ́wọ́ Pahlavi dynasty; àti Afghanistan bẹ̀rẹ̀ sí ní lòó ní 2004 lẹ́yìn ìwólulẹ̀ ìjọba Tàlìbánì.
Orílẹ̀-èdè | Ọjọ́ọdún tó bẹ̀rẹ̀ | Irú ìjọba |
---|---|---|
Islamic Republic of Afghanistan
| 7 December 2004 | Unitary presidential republic |
Islamic Republic of Iran | 1 April 1979 | Unitary Khomeinist presidential republic (de facto theocratic-republican subject to a Supreme Leader) |
Islamic Republic of Mauritania | 28 November 1960 | Unitary semi-presidential republic |
Islamic Republic of Pakistan | 23 March 1956 | Federal parliamentary constitutional republic |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Orílẹ̀-èdè olómìnira onímàle, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.