Afghanístàn

Afghanístàn ( /æfˈɡænᵻstæn,_æfˈɡɑːnᵻstɑːn/; Pashto/Dari: افغانستان, Pashto: Afġānistān , Dari: Afġānestān Àdàkọ:IPA-fa), àlòṣiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Afghanístàn, ni is a orílẹ̀-èdè onílẹ̀bodè ní Gúúsù àti Àrin Ásíà.

Afghanístàn ní bodè mọ́ Pakistan ní ìlà-òrùn àti ní gúúsù; mọ́ Iran ní ìwọ̀-òrùn; mọ́ Turkmenistan, Uzbekistan, àti Tajikistan ní àríwá; àti mọ́ Ṣáínà ní àríwá-ìlàòrùn. Gbogbo ilẹ̀ ibẹ̀ fẹ̀ tó 652,000 square kilometers (252,000 sq mi), orílẹ̀-èdè olókè ní tó ní ilẹ̀ pẹpẹ ní apá àríwá àti gúúsù-ilàòrùn. Kabul ni olúìlú àti ilú tótóbijùlọ níbẹ̀. Iye aráàlú ibẹ̀ fẹ́ ẹ̀ pọ̀ tó 32 mílíọ́nù, tí wọ́n jẹ́ ẹ̀yà àwọn Pashtun, Tajik, Hazara àti Uzbek.

Islamic Republic of Afghanistan

  • د افغانستان اسلامي جمهوریت (Pashto)
  • Da Afġānistān Islāmī Jumhoryat
  • جمهوری اسلامی افغانستان (Dari)
  • Jomhūrī-ye Eslāmī-ye Afġānestān
Flag of Afghanístàn
Motto: لا إله إلا الله، محمد رسول الله
"Lā ʾilāha ʾillā llāh, Muhammadun rasūlu llāh"
"There is no God but Allah; Muhammad is the messenger of Allah." (Shahada)
Orin ìyìn: Millī Surūd
ملي سرود
("National Anthem")
Afghanístàn
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Kabul
33°N 65°E / 33°N 65°E / 33; 65 65°E / 33°N 65°E / 33; 65
Official languages
Dari 27 million (77%) (L1 + L2), Pashto 16.8 million (48%)
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
  • 42% Pashtun
  • 27% Tajik
  • 9% Hazara
  • 9% Uzbek
  • 4% Aimaq
  • 3% Turkmen
  • 2% Baloch
  • 1% others
Ẹ̀sìn
  • 99.7% Islam (official)
  • 0.3% others
Orúkọ aráàlúAfghan
ÌjọbaUnitary presidential Islamic republic
• President
Ashraf Ghani
• 1st Vice President
Amrullah Saleh
• 2nd Vice President
Sarwar Danish
AṣòfinNational Assembly
• Ilé Aṣòfin Àgbà
House of Elders
• Ilé Aṣòfin Kéreré
House of the People
Formation
• Hotak Empire
21 April 1709
• Durrani Empire
July 1747
• Emirate
1823
• Recognized
19 August 1919
• Kingdom
9 June 1926
• Republic
17 July 1973
• Current constitution
26 January 2004
Ìtóbi
• Total
652,230 km2 (251,830 sq mi) (40th)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• 2019 estimate
32,225,560 (44th)
• Ìdìmọ́ra
46/km2 (119.1/sq mi) (174th)
GDP (PPP)2018 estimate
• Total
$72.911 billion (96th)
• Per capita
$2,024 (169th)
GDP (nominal)2018 estimate
• Total
$21.657 billion (111st)
• Per capita
$601 (177th)
Gini (2008)positive decrease 27.8
low · 1st
HDI (2018) 0.496
low · 170th
OwónínáAfghani (Afs) (AFN)
Ibi àkókòUTC+4:30 Solar Calendar (D†)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù+93
ISO 3166 codeAF
Internet TLD.af افغانستان.

Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tí wọ́n sọ pé ó wà ní ìlú yìí lé díẹ̀ ní mílíònù mọ́kànlélógún (21,017.000). Èdè tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí tó àádọ́ta ṣùgbọ́n ìlàjì nínú àwọn tí ó wà ní ìlú náà ni ó ń sọ páṣítọ̀ (Pashto) tí òun àti Dárì jọ jẹ èdè ìjọba (official language). Dárì (Dari) yìí nì orúkọ tí wọ́n ń pe Persian (Pásíà) ní Afuganísítàànù. Dárí yìí ṣe pàtàkì gan-an ni gẹ́gẹ́ bí èdè tí ìjọba ń lò (lingua franca). Fún ti òwò tí ó jẹ mọ gbogbo àgbáyé, èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n ń sọ ní ìlú yìí ni Tadzhik, Uzbek, Turkmen, baluchi, Brachic àti pashayi


Itokasi



Tags:

Central AsiaIranKabulPakistanPashtoSouth AsiaTajikistanTurkmenistanUzbekistanen:Wikipedia:IPA for EnglishṢáínà

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Sean ConneryInternetÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáOlúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ÌwéÒgún LákáayéWolframuOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìDoctor BelloFáwẹ̀lì YorùbáMurtala MuhammadÒrùnIkúFrancis BaconÌpínlẹ̀ ÈkìtìOpeyemi AyeolaNew JerseyJakartaAkanlo-edeOṣù Kínní 15CalabarAtlantaÌsirò StatistikiỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Ali Abdullah SalehÌṣèlú ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàlÀríwá Amẹ́ríkàPópù Gregory 16kMathimátíkì3GP àti 3G2PornhubOranmiyanVladimir NabokovBeirutLebanonAÒrò àyálò YorùbáÌṣeọ̀rọ̀àwùjọÀgbérò PythagorasOrílẹ̀ èdè AmericaLítíréṣọ̀Pópù Benedict 16kÌbálòpọ̀ISO 3166-1 alpha-2Ìjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020Yunifásítì Harvard22 DecemberBùrúndìÌtànThomas CechÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàWeb browser1151 IthakaEzra OlubiFrancisco León FrancoẸranko afọmúbọ́mọMyanmarAbubakar MohammedOṣù Kínní 7Salvador Allende🡆 More