Monica Bolna'an Dongban-Mensem CFR (ọjọ́-ìbí: ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹfà ọdún 1957) jẹ́ adájọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Ó jẹ́ Ààrẹ ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ní Nàìjíríà. Ìpinnu yíyán rẹ̀ jẹ́ ìfọwọ́sí ní ọjọ́bọ̀, oṣù kẹfà ọjọ́ kọkànlá, ọdún 2020.
Ní oṣù kẹwàá ọdún 2022, ọlà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kan ti Alákoso ti Àṣẹ ti ìjọba àpapọ̀ (CFR) ni a fún Monica nípasẹ̀ Ààrẹ Muhammadu Buhari.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Monica Dongban-Mensem, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.