Mfon Sunday Udoka (tí a bí ní ọjọ́ kerin-dín-lógún, oṣù kẹfà ọdún 1976) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà-Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀rí agbábọ́ọ́lù inú agbọ̀n tí ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ olùkọni fún ẹgbẹ́ bọ́ọ́lù inú agbọ̀n ti àwọn obìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, D'Tigress.
Tí a bí ní Portland, Oregon, Udoka parí ilé-ìwé gíga Benson Polytechnic (1994) ní Portland ṣáájú kí ó tó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga DePaul ní Chicago, Illinois láti ọdún 1994 sí ọdún 1998. Ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí olùkọni àti òṣèré NBA tẹ́lẹ̀ Ime Udoka.
Forward | |
Personal information | |
---|---|
Born | Oṣù Kẹfà 16, 1976 Portland, Oregon, U.S. |
Nationality | American / Nigerian |
Listed height | 6 ft 0 in (1.83 m) |
Listed weight | 187 lb (85 kg) |
Career information | |
High school | Benson (Portland, Oregon) |
College | DePaul (1994–1998) |
NBA draft | 1998 / Undrafted |
Career history | |
1998 | Detroit Shock |
2003 | Houston Comets |
2004 | Los Angeles Sparks |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Mfon Udoka, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.