Minnie Joycelyn Elders (abiso Minnie Lee Jones; August 13, 1933) je is an American oniwosan omode ati alakoso eto ilera igboro.
O je ogagun igbakeji adari ni ile-ise awon omose alafunse ise ilera igboro ati omo Afrika Amerika akoko to je yiyan sipo gege bi Oniwosan Agba Orile-ede Amerika, o fi ipo yi sile ni 1994. Lowolowo Elders je ojogbon eniowo ninu eko iwosan omode ni Yunifasiti Arkansas fun Sayensi Oniwosan.
Joycelyn Elders | |
---|---|
15th Surgeon General of the United States | |
In office September 8, 1993 – December 31, 1994 | |
Ààrẹ | Bill Clinton |
Asíwájú | Robert A. Whitney (acting) |
Arọ́pò | Audrey F. Manley (acting) |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Minnie Lee Jones 13 Oṣù Kẹjọ 1933 Schaal, Arkansas, U.S. |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Democratic |
Military service | |
Branch/service | Public Health Service Commissioned Corps, United States Public Health Service |
Years of service | USA: 1953–1956 |
Rank | USPHS: Vice Admiral |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Joycelyn Elders, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.