Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì

Ile Ìjoba Songhai, tàbí Ile Ìjoba Songhay, je ile-ijoba ni iwoorun Afrika ní ìgbàkan rí.

Lati ibere orundun 15th titi de opin orundun 16th, Songhai je ikan ninu awon ile ìjoba Afrika tí ò tobi julo ni itan aye. Oruko re wá lati oruko awon eya eniyan to siwaju nibe, eyun awon Songhai. Oluilu re wa ni ilu Gao, nibi ti ile-ijoba Songhai kekere kan ti wà lati orundun 11th. Ibujoko agbara re wa ni koro apa Odo Oya ni orile-ede Niger loni ati Burkina Faso.

Ilé Ìjoba Songhai
Ìjoba
Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì
c. 1340–1591 Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì
 
Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì
Ilẹ̀ Ọbalúayé Sọ́ngháì
Location of Ilé Ìjoba Songhai tabi Orílè Songhai
The Songhai Empire, (ca. 1500)
Capital Gao
Language(s) Songhai
Religion Islam (Èsin Ìmàle)
Government Ije Oba
Sonni; later Askiya
 - 1468-1492 Sunni Ali (first)
 - 1588-1591 Askia Mohammad I (last)
History
 - Orílè Songhai bèrè ní Gao c.1000
 - Songhai gba òmìnira l'ówó Ìjoba Mali pátápátá c. 1340
 - Songhai fi ogun bere si ni fe ibudo won 1460
 - Ìgba ìjoba l'owo Ìdíle Sunni 1493
 - Ìdíle Saadi pa Orílè Songhai run 1591
 - Ifi ìdi Orílè Songhai mule ìjoba Dendi 1592

The Dendi Kingdom ends 1901

Area
 - 1500 1,400,000 km2 (540,543 sq mi)
 - 1550 800,000 km2 (308,882 sq mi)
Currency Cowries
(wura, iyò ati copper ni wón n ná)
Warning: Value specified for "continent" does not comply



Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

AfricaBurkina FasoGaoNigerNiger River

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Jẹ́ọ́gráfì ilẹ̀ NàìjíríàTim RobbinsGerhard DomagkG.729Yoruba2 MarchYemoja2516 Roman(4477) 1983 SBÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáNneka EzeigboWasiu Alabi PasumaAK-47Latefa AhrarTorxThe New York TimesGeorgiaCalabarList of countries by populationArtaxerxes IIIOrílẹ̀ èdè AmericaAlumíníọ̀mùAlassane OuattaraList of human evolution fossilsBitcoinÀtòjọ Àwọn Olú-ìlú Àwọn Orílẹ̀-èdè Ní ÀgbáyéÀwùjọJean-Paul SartreAgbẹjọ́rò Àgbà ilẹ̀ NàìjíríàÀwọn Erékùṣù KáímànTristan da CunhaSantos AcostaBùlgáríàMicrosoft Windows.srΜ-law algorithmWest BengalÀjọni àwọn Orílẹ̀-èdè(188721) 2005 UUPaul KehindeÌpínlẹ̀ BauchiKesiumOlódùmarèEfinrinDaisy DucatiART X LagosLáọ̀sTopic MapsPatience Okon GeorgeArgẹntínàIndonésíàLeo StraussGbólóhùn YorùbáMy Siblings and ISão Tomé and PríncipeGideon OkekeẸtuChristmasAdvanced Audio CodingOregonPaul von Hindenburg🡆 More