Iddi Basajjabalaba Memorial Library

Iddi Basajjabalaba Memorial Library jẹ́ ilé ìkàwé kan náà ní Kampala International University ní Kansanga, Kampala, orílẹ̀ èdè Uganda, tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 2001.

Wọ́n mọ̀ ọ́ tẹ́lẹ̀ sí ilé ìkàwé Kampala International University. Orúkọ rẹ̀ yí padà ní ọdún 2013 ní ìrántí olóògbé Iddi Basajjabalaba, bàbá alága ẹgbẹ́ tí ó ń rí sí ìdarí ilé ìkàwé náà, Hassan Basajjabalaba.

Ìdarí ilé ìkàwé náà

Ilé ìkàwé náà wà lábẹ́ ìdarí olùdarí àgbà ilé ìwé náà, Prisca Tibenderana, tí ó ń jábọ̀ fún adarí ètò ẹ̀kọ́ ní Kampala International University.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

KampalaUganda

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

18 March27 OctoberApágúúsù EuropeBenjamin DisraeliTwitterUganda21 MarchMayotteTànsáníàẸ̀rúndúnGbNicos AnastasiadesTennesseePọ́rtúgàlPaul-Henri MathieuGerald FordÈdè Pẹ́rsíàOrin hip hopWàsíù Àlàbí PasumaÀdírẹ́ẹ̀sì IPChukchi SeaAyoka Olufunmilayo AdebamboRománíàLyndon B. JohnsonMahmoud AhmadinejadAustrálásíà17 DecemberCDaniel D. TompkinsMendeleviumSaarlandÀgbájọ Káríayé fún Ìṣọ̀págunPópù FabianJacqueline Kennedy OnassisAkọ̀wé-Àgbà Àjọni àwọn Orílẹ̀-èdèDubaiAmẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lùIṣẹ́ Àgbẹ̀LeadÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunTibetÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ RùwándàFrancis 1k ilẹ̀ FránsìOhioJudi DenchÀdàbàKárbọ̀nùAdolf Otto Reinhold WindausFacebookÌwọòrùn Bẹ̀ngálÀgbọ̀rínIlẹ̀ YorùbáÀgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn OlóróH.264/MPEG-4 AVCJacob BernoulliGeorgiaPeso ArgẹntínàWolframuRobert Robinson (scientist)Shche ne vmerla UkrainyGíwá yunifásítìMàríà (ìyá Jésù)Dagobert 1kOṣù Kínní 8Pavel CherenkovNàìjíríàSeptimius SeverusÈbu🡆 More