Eṣinṣin

Àwọn eṣinṣin jẹ́ kòkòrò ninu ito awon oníyẹ̀ẹ́meji (Diptera; lati ede Griiki di = meji, ati ptera = iye).

Iyato won kedere si awon kokoro miran ni esinsin ni iye ifo meji ni aya-arin ati pair of haltere meji, to wa lati iye eyin, ni aya-ikeyin. (Awon irueda esinsin kan yato nitoripe won ko le fo). Awon kokoro miran ti won tun ni iye to unsise ati iru halteres kan ni Strepsiptera, won si yato si awon esinsin nitoripe awon Strepsiptera ni halteres won ni aya-arin ati iye ifo won ni aya-ikeyin.

Eṣinṣin/Eṣin
Eṣinṣin
Anatomy of a Housefly. I: head; II: thorax III: abdomen. — 1: prescutum; 2: anterior spiracle; 3: scutum; 4: basicosta; 5: calypters; 6: scutellum; 7: wing vein; 8: wing; 9: abdominal segment; 10: haltere; 11: posterior spiracle; 12: femur; 13: tibia; 14: spur; 15: tarsus; 16: propleuron; 17: prosternum; 18: mesopleuron; 19: mesosternum; 20: metapleuron; 21: metasternum; 22: Compound eye; 23: arista; 24: antenna; 25: maxillary palps; 26: labium; 27: labellum; 28:pseudotracheae.
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Arthropoda
Ẹgbẹ́:
Subclass:
Pterygota
Infraclass:
Neoptera
Superorder:
Endopterygota
Ìtò:
Diptera

Linnaeus, 1758
Suborders

Nematocera (includes Eudiptera)
Brachycera

Eṣinṣin
Aworan iru esinsin orisirisi merindinlogun


Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Rọ́síàISO 3166Kelly RowlandPalẹstínìGiosuè CarducciCristiano RonaldoÈdè JavaÍsráẹ́lìCaliforniaÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánWikipẹ́díà l'édè YorùbáKatẹrínì 2k ilẹ̀ Rọ́síàBimbo AdemoyeẸ́gíptì Ayéijọ́unKen Saro-WiwaArgẹntínàPonun StelinTunde IdiagbonToyotaLebanonÌbálòpọ̀ISO 12207.idBermudaInternetOSI modelISO 3166-1Bob McGrathB.B. KingWorld Wrestling EntertainmentHelsinkiÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáPópù Alexander 6kSammy Davis, Jr.FísíksìZagreb27 MarchUsher.toÌtàn àkọọ́lẹ̀ YorùbáÌkàrẹ́-AkókoGeorges ClemenceauKàmbódíàUsain BoltỌjọ́ 18 Oṣù KẹtaSonyKàsínòSkopjePonnaNigerian People's PartyOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàHydrogenWikiAudu OgbehRosa LuxemburgRichard AxelIsraelMọ́remí ÁjàṣoroISO 14644Ibadan Peoples Party (IPP)Tsẹ́kì OlómìniraÀwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáMediaWikiÌṣọ̀kan EuropeJ. R. R. TolkienGujaratCapital cityẸyọ tíkòsíParisiNew YorkChika IkeKọ̀nkọ̀🡆 More