Kẹ́nyà Ìgbéríko Àrin

Ìgbéríko Àrin Kenya ni agbegbe 'keta to o kere ju lo ni Orile Ede Kenya, lehin agbegbe Nairobi, ati agbegbe Iwo Oorun, pelu Àpapọ̀ iye ààlà 13,191 km2 (5,093.1 sq m).agegbe naa wa ni iha Ariwa si ilu Nairobi, ati iha Iwo O'orun si oke Kenya.

Ni Ikaniyan to odun 2009, agbegbe naa ni iye eniyan Olùgbé 4,383,743. Olu ilu agbegbe naa ni ilu Nyeri.Agbegbe aarin Kenya je Ile isenbaye ti awon eya Kikuyu.

Ìgbéríko Àrin
Ìgbéríko
Location in Kenya.
Location in Kenya.
CountryKẹ́nyà Ìgbéríko Àrin Kenya
No. of districts:12
CapitalNyeri
Area
 • Total13,191 km2 (5,093 sq mi)
Population
 (2007)
 • Total4,145,000
Time zoneUTC+3 (EAT)
Kẹ́nyà Ìgbéríko Àrin
Central Province of Kenya surrounds its capital, Nyeri, and includes slopes of Mount Kenya (click to enlarge map).

Kilimati

kilimati Agbegbe aarin Kenya ni akoto tutu ju awon agbegbe iyoku orile Ede naa lo, nitori wipe, agbegbe naa wa no ile giga ju awon agbegbe 'yoku lo.Ojo maa n ro ni asiko meji ninu Odun. L'akoko lati osu Iketa(March), so osu karun-un(May), ati asiko elekeji to o bere ni Osu Kewaa(october} ati osu Ikakanla(November). Awon ojo akoko elekeji wonyii ni a mo si awon ojo asiko kukuru

Imo akoto

Itokasi

Tags:

KenyaNairobiOlùgbé

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

EukaryaÌlàoòrùn Jẹ́mánìMichael JordanÀlọ́Àsìá Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ MakẹdóníàÈbuPeter FatomilolaÀjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàPsamtik 1kYorùbáAdenike OlawuyiLítíréṣọ̀LogicAnatole FranceBerneIrinGíríìsìMọ́skòAyéAuguste Beernaert2437 Amnestia29 AprilỌjọ́ ÀìkúBaruch SpinozaElisabeti KejìMackenzie BowellArizonaHTMLSaint Helena, Ascension àti Tristan da CunhaAzareCalabarLèsóthòHermann HesseOṣù KọkànláIodineÀṣà YorùbáÌwé àwọn Onídàjọ́Vladimir LeninH. H. AsquithManifẹ́stò KómúnístìIlé-Ifẹ̀Gulf Pẹ́rsíàWikimediaChristian BaleParáPorto NovoRachel BaardÍsráẹ́lìIkọ́ÀdánidáỌdẹIowaLeadGrace AnigbataÒṣèlú aṣojúEzra OlubiAntárktìkìỌbaPópù Gregory 7kMadridTaofeek Oladejo ArapajaBitcoinISO 15022ISO 3166-3Operating SystemQuickTimePierre NkurunzizaṢáínàWaterLáọ̀s🡆 More