Banana Island, Lagos: Erukusu atowoda ní ìpínlè Eko

Banana Island jẹ erekuṣu atọwọda ti o wa nitosi Ikoyi, ìpínlè Eko, Naijiria.

A fun ní oruko náà nitori boserí. A dá erukusu náà fún igbé àti láti jé ojà fun títà ríràrira, o ni àwon ilé igbé, ilé itaja àti ilé idaraya.

Itan kíkó rè

Banana Island, Lagos: Erukusu atowoda ní ìpínlè Eko 
Lagoon City-Twin Towers - Adeleke / Yamasaki
Banana Island, Lagos: Erukusu atowoda ní ìpínlè Eko 
Lagoon City - Eriali Asokagba
Banana Island, Lagos: Erukusu atowoda ní ìpínlè Eko 
Lagoon City - Architectural Eto
Banana Island, Lagos: Erukusu atowoda ní ìpínlè Eko 
Lagoon City - Lagoon Side Wo

Ologbe Adebayo Adeleke ni ó ya àwòrán Erukusu Banana Island tí a pè ní Lagoon city nígbà kíkó rè. Adebayo ni Alakoso ilé-isé City Property Development Ltd.

Banana Island, Lagos: Erukusu atowoda ní ìpínlè Eko 
Iwo Banana Highland tí a yà láti afara Lekki-Ikoyi .

Banana Island jẹ erekusu atowoda ni Ipinle Eko, Naijiria ti ìrísí rè dabi ti Ogede O wa ni orí Adagun Èkó o si ní afara to so pò mó Erukusi Ikoyi. Ilé-isé Lebanon-Nigeria Chagoury Group ni o kọ erekuṣu naa pèlú ajọṣepọ Federal Ministry of Works and Housing.

Itobi erukusu náà to awọn 1,630,000 square meter asì pin pin si awọn ploti 536 A pese awọn olugbe pẹlu awọn ohun elo bi omi àti iná àti nẹtiwọki satẹlaiti ibaraẹnisọrọ.

Àwon ilé-isé nla nla ni orilẹ-ede Naijiria bi- Etisalat Nigeria, Airtel Nigeria, Ford Foundation Nigeria ati Olaniwun Ajayi & CO kalè sí Banana Island.

Díè ninú awọn olugbe ibè

Àwon Ìtókasí

Tags:

NàìjíríàÌkóyí

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Dorcas Coker-AppiahISO 8000Eugenio MontaleHilary SwankÀrúbàWikimediaDiamond Jackson.blGloria EstefanOwe YorubaCharlemagneDolby DigitalTurkeyÍsráẹ́lìAgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Abẹ́òkútaOpen Amẹ́ríkà 1985 − Àwọn Obìnrin Ẹnìkan4 JuneWikisourceRupee ÍndíàỌ̀rọ̀ayéijọ́unAdekunle GoldDonald TuskAnschlussÌlaòrùn ÁfríkàNancy ChartonÀkójọ átọ̀mùIkúInternetFilipínìIllinoisÌpínlẹ̀ Òndó.fmOṣù Kejì28 MarchÀrún èrànkòrónà ọdún 2019Mọ́skòÀgbáyéJapan8 SeptemberNọ́rwèyApágúúsù ÁfríkàMadagásíkà6 AugustPaul NewmanKòréà ÀríwáPópù Adrian 3k.afSanusi Lamido SanusiArewa 24LèsóthòOgunTop-level domainQBarack ObamaPyongyangFrederick North, Lord NorthG🡆 More