Amarachi Nwosu (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù Kẹ̀sán ọdún 1994) jẹ́ ayàwòrán, eléré àti akọ̀wé.
Ó jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Òun ni oludasile Melanie Unscripted. Eré ìtàn, Black in Tokyo tí ó ṣe tí farahàn ni International Centre of Photography ni ọdún 2017 ni ìlú New York , ó sì tí farahàn ni Ultra Super New Gallery ni ìlú Harajaku.
Amarachi Nwosu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 29 September 1994 Washington, D.C., U.S | (ọmọ ọdún 29)
Orílẹ̀-èdè | Nigerian-American |
Ẹ̀kọ́ | Temple University |
Iṣẹ́ | Photographer, film maker |
Works | Black In Tokyo |
Website | amarachinwosu.com |
Àwọn òbí Amarachi jẹ́ ọmọ íbò. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Temple University ni ilẹ̀ Philadelphia.
Ní ọdún 2019, Malala Yousafzai tí ó gbà ẹ̀bùn Nobel laureate youngest winner péè Nwosu láti ya àwọn àwòrán ní ìrìnàjò rẹ sì Tokyo.Òun ni ó ya àwòrán fún àwọn ẹ̀yán gbajúmọ̀ bii Náómì Campbell nígbà tí ó wà sì ìlú Èkó ni Nàìjíríà àti Ebonee Davis. Ó sì ti ṣe adarí fún àwọn ère kékeré fún àwọn ilé iṣẹ́ bíi Nike ni Nàìjíríà. Ó ti si ṣé pelu àwọn olórin bíi Mr Eazi, Yxng Bane, Nonso Amadi, Odunsi The Engine, Santi, Kwesi Arthur àti Tóbi Lou. Ó si ṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi ayàwòrán fún Childish Gambino ni ọdún 2018. Òun ni ayàwòrán fún ètò The Fader tí wọn ṣe ni orílẹ̀ èdè Japan. Ni ọdún 2017, òun àti Stella McCartney jọ ní àríyànjiyàn.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Amarachi Nwosu, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.