Abdullahi Umar Ganduje, OFR tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1945 (25 December 1945) jẹ́ olóṣèlú àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kánò lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọdún 2015.
Kí ó tó di Gómìnà, òun ni igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano, lọ́dún 1999 sí 2003 àti 2011 sí 2015.
Abdullahi Umar Ganduje OFR | |
---|---|
Abdullahi Umar | |
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kánò | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2015 | |
Asíwájú | Rabiu Kwankwaso |
Deputy Governor of Ìpínlẹ̀ Kánò | |
In office 29 May 1999 – 29 May 2003 | |
Arọ́pò | Magaji Abdullahi |
In office 29 May 2011 – 29 May 2015 | |
Asíwájú | Abdullahi Tijjani Gwarzo |
Arọ́pò | Prof. Hafizu Abubakar |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kejìlá 1949 Ganduje, Dawakin Tofa, Ìpínlẹ̀ Kánò |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Hafsat Umar |
Residence | Kano, Nàìjíríà |
Alma mater | Ahmadu Bello University Bayero University Kano University of Ibadan |
Occupation | Politician |
Profession | Administrator |
Website | ganduje.com.ng |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Abdullahi Umar Ganduje, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.