139 Julewa jẹ́ ìgbàjá ìsọ̀gbé oòrùn kékeré dúdú tí ó sì fẹ̀. Ó jẹ́ àkọ́kọ́ ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tí wọ́n máa ṣàwárí rẹ̀ ní orílẹ̀ èdè China. Àlejò Onímọ̀ ìwòràwọ̀, James Craig Watson ọmọ Amẹ́ríkà ní o ṣàwárí rẹ̀ ní Beijing ní Ọjọ́ kẹwá Oṣù kẹ́wá Ọdún 1874.
Ìkọ́kọ́wárí and designation | |
---|---|
Kíkọ́kọ́wárí látọwọ́ | James Craig Watson |
Ọjọ́ ìkọ́kọ́wárí | 10 October 1874 |
Ìfúnlọ́rúkọ | |
Minor planet category | Main belt |
Àwọn ìhùwà ìgbàyípo | |
Àsìkò 31 July 2016 (JD 2457600.5) | |
Aphelion | 3.26884 AU (489.012 Gm) |
Perihelion | 2.29261 AU (342.970 Gm) |
Semi-major axis | 2.78073 AU (415.991 Gm) |
Eccentricity | 0.17553 |
Àsìkò ìgbàyípo | 4.64 yr (1693.7 d) |
Average orbital speed | 17.72 km/s |
Mean anomaly | 60.2817° |
Inclination | 10.9127° |
Longitude of ascending node | 1.83417° |
Argument of perihelion | 165.566° |
Àwọn ìhùwà àdánidá | |
Ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ | 156.60±2.8 km 161.43±7.38 km |
Àkójọ | 5.54±2.20×1018 kg |
Iyeìdáméjì ìṣùpọ̀ | 2.51±1.05 g/cm3 |
Equatorial surface gravity | 0.0438 m/s² |
Equatorial escape velocity | 0.0828 km/s |
Rotation period | 20.991 h (0.8746 d) |
Geometric albedo | 0.0557±0.002 0.0444±0.0164 |
Ìgbónásí | ~167 K |
Spectral type | CP (Tholen) |
Absolute magnitude (H) | 7.78, 7.924 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article 139 Juewa, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.