Ìwé Hóṣéà jẹ́ ìwé Bíbélì Mímọ́ tó ń ṣàfiwé ìfẹ́ Hóṣéà sí aya rẹ̀ tó dẹ́ṣẹ̀ àgbèrè, tí ó ṣì fẹ́ràn tó sì gbà tọwọ́-tẹsẹ̀ padà.
Tí ó sì jẹ́ wí pé, ní tòótọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì apá àríwá Jerúsálẹ́mù ní ọ̀rọ̀ náà ń pàrọwà sí pé àánú Ọlọ́run ń bẹ láti gbàlà, ràpadà, túnṣe àti fẹ́ gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀ káàkiri wà títí tí wọ́n bá tan orísun wọn padà sí i.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Ìwé Hóséà, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.