Ọ̀rọ̀ayéijọ́un

Ọ̀rọ̀ayéijọ́un (Archaeology, tabi archeology lede Geesi lati ede Griiki ἀρχαιολογία, archaiologia – ἀρχαῖος, arkhaios, ayeijoun; and -λογία, -logia, -logy) je agbeka awujo omoniyan, lakoko nipa iwari ati ituyewo asa ohun-ini ati awon data ayika ti won fi seyin, ti ninu won je iseowo, onaikole, onidajuayika ati ojuile asa (eyun akoole oloroayeijoun).

Nitoripe oroayeijoun lo orisirisi igbese otooto, o se e gba bi sayensi ati bi awon eko omoniyan, be sini ni Amerika won gba bi eka oroomoniyan, botilejepe ni Europe won gba bi eka-eko to dawa.

Ọ̀rọ̀ayéijọ́un
Ilétíátà ayéijóun ìgbà Romu, ni Alexandria, Egypt


Itokasi

Tags:

Ancient GreekEnglish languageEuropeHumanScienceSocietyUnited States

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

CaracasRọ́síàISO 8601KánádàWikipediaBaltimoreFáwẹ̀lì YorùbáỌ̀rànmíyànJésùAustríàLyndon B. JohnsonOhun ìgboroÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéNew YorkÌgbéyàwóẸranko afọmúbọ́mọÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánOrílẹ̀Ere idarayaEugene O'NeillSARS-CoV-2OSI modelOlóṣèlúAbubakar MohammedMyanmarÌwéInternet Relay ChatAli Abdullah SalehPakístànSaadatu Hassan LimanIndonésíàLudwig van BeethovenAbdulaziz UsmanOmiDoctor BelloYemojaMao ZedongGuinea-BissauOṣù KẹtaÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàÌran YorùbáWiki CommonsAustrálíàBeirutNew JerseyKọ̀mpútàOjúewé Àkọ́kọ́Onome ebiIHuman Rights FirstÒfinAbdullahi Ibrahim GobirÈdè Rọ́síàOranmiyanCalabar🡆 More