Àwọn Yorùbá Tó Ń Ṣòwò Ẹrú Gba Ojú Omi Atlantic

Àwọn Ẹ̀yà Yorùbá kópa tó pọ̀ nínú okoòwò ẹrú ṣíṣe gba ojú omi Atlantic, pàápàá jù lọ nípa àṣà àti ètò-ọ̀rọ̀-ajé ní ọdún 1400 sí 1900 CE.

Àwọn ìlú tí Ọ̀yọ́ ń pàṣẹ lé

Bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 1400 síwájú, àwọn ìlú tí ìṣèjọba Ìlú Ọ̀yọ́ ń pàṣẹ fún jẹ́ kí Èdè Yorùbá di èdè ìṣèjọba káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè kan ní ìwọ̀-oòrùn Africa. Ní gẹ̀gẹ̀rẹ́ òpin sẹ́ńtúrì méjìdínlógún (18th century), wọn ò mójú tó àwọn jagunjagun Ọ̀yọ́ mọ́ nítorí pé kò fi bẹ́ẹ̀ sí àwọn ìlú tí wọ́n fẹ́ gbà mọ́ sábẹ́ àṣẹ Ìlú Ọ̀yọ́ . Dípò èyí, Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní tẹra mọ́ Okoòwò Ẹrú káàkiri àgbègbè ilẹ̀-adúláwò, pàápàá jùlọ lápá Ìwọ̀-oòrùn Afrika. Europeans bringing salt arrived in Oyo during the reign of King Obalokun. Nítorí gbajúmọ̀ wọn nínú Okoòwò Ẹrú, àwọn olókoòwò ẹrú Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní bá àwọn Òyìnbó Ìlẹ̀ Europe ṣòwò ẹrú ní Porto Novo ati Whydah. Ní àkókò yìí ni àwọn Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní tá àwọn ẹrú àti àwọn ọ̀daràn tí wọ́n bá mú fún àwọn olókoòwò ẹrú láti orílẹ̀-èdè Nederland àti Portugal.

Ipa àṣà

Ipa tí àṣà, pàápàá jù lọ kò kéré rárá, ní àfikún sí ipa tí àṣà kó nínú okoòwò ẹrú, àti nígbà tí ó ń tẹ̀síwájú, lórí oúnjẹ àti èdè ìbílẹ̀ Afrika àti àwọn òyìnbó, kíkó àṣà àwọn Yorùbá wọ̀lú fara hàn lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú Ẹ̀sìn Yorùbá bí ó ṣe jẹyọ nínú àwọn ẹ̀sìn bíi Santería, Candomblé Ketu, àti àwọn ìbọ mìíràn.

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

ManhattanMọ́remí ÁjàṣoroHọ́ng KọngSani AbachaÌjíptìANSI escape code.idUsherThe NetherlandsÈdè ÍtálìJ. R. R. TolkienFemi GbajabiamilaẸkún ÌyàwóStockholmOrílẹ̀-èdè Olómìnira àwọn Ará ilẹ̀ ṢáínàOSI modelÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunṢàngóAvicenna(9981) 1995 BS3United Arab EmiratesOgun Gulf Pẹ́rsíàSpainFrancisco Diez CansecoOrílẹ̀-èdè Olómìnira Àrin Ilẹ̀ ÁfríkàOrúkọ YorùbáSantos AcostaAbidi BrailleTennesseeÌsirò StatistikiỌbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀Joe BidenWikinewsÈkóGiosuè CarducciẸ̀sìn IslamÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ IndonésíàNikarágúàKuwaitOpeyemi AyeolaAjọfọ̀nàkò Àsìkò KáríayéWorld Wrestling EntertainmentNetherlands2293 GuernicaJúpítérìNew Jersey29 JanuaryGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèTwitterBermudaKen Saro-WiwaAmẹ́ríkàn futbọ́ọ̀lùTurkeyKọ̀nkọ̀IsraelMargaret ThatcherPalestineKòkòròNeil ArmstrongOrílẹ̀ èdè AmericaDavid CameronFriedrich HayekAtlanta1 E11 m²JakartaOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìNẹ́dálándìÀàrẹ ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàISO/IEC 27005Sikiru Ayinde Barrister🡆 More