Okoẹrú jẹ́ ìṣe ayé àtijọ́ tí àwọn ènìyàn kan máa ń ṣe káràkátà ọmọ ènìyàn mìíràn fún àwọn alágbára tàbí àwọn òyìnbó amúnisìn.
Nínú okowò ẹrú, ọmọ ènìyàn ni ọjà tí wọ́n ń tà. Wọ́n máa ń kó àwọn ènìyàn tí wọ́n tà lẹ́rú lọ ṣiṣẹ́ oko àti àwọn ìṣe líle ni ìlú òyìnbó. Àwọn tí wọ́n bá kò lẹ́rú kì í ní òmìnira kankan bẹ́ẹ̀ sì ni wọ́n fi wọ́n ṣiṣé ní tipátipá.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Okoẹrú, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.