Vanderkloof Dam

Vanderkloof Dam (ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ PK Le Roux Dam) wà ní ìsúnmọ́ 130 kilometres (81 mi) ìbọ́sílẹ̀ láti Gariep Dam àti pé odò Orange ní apá Gúúsù ilẹ̀ Áfíríkà ni ó ti ṣàn wá.

Vanderkloof Dam jẹ́ ìdídò kejì tí ó tóbi jùlọ ní apá Gúúsù ilẹ̀ Áfíríkà (ìwọ̀n), tí ó ní odi ìdidò tí ó ga jùlọ ní Orílẹ̀-èdè ní 108 metres(ìwọn 354). Ọdún 1977 ni wọ́n ṣí ìdídò náà; ó ní agbára ti 3,187.557 million cubic metres (2,584,195 acre⋅ft) àti agbègbè pẹrẹsẹ ti 133.43 square kilometres (51.52 sq mi) nígbàtí ó bá kún. Àwọn odò mìíràn tí ó ń ṣàn sínú ìdídò yìí ni Odò Berg, àwọn ìṣàn méjì tí kò ní orúkọ tí ó ń ṣàn láti ọ̀nà Reebokrand, Odò Knapsak, Paaiskloofspruit, OdòSeekoei , Kattegatspruit àti Odò Hondeblaf, ní ìtọ́sọ́nà aago.

Vanderkloof Dam
Àwòrán Vanderkloof Dam

Ìlú VanderKloof ti fi ìdí múlẹ̀ sí apá òsì etídò ti ìdídò náà, pẹ̀lú ọ̀nà àbáwọlé ti ìlú náà wà ní ọ̀nà tí ó wá láti odi ìdídò náà, pẹ̀lú àwọn ibi ìsinmi àti àwọn pápá ìtura bí i Rolfontein Nature Reserve ( Àwọn fọ́tò Wiki Commons )

Àwọn àwòrán

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Marc Fleurbaey17 MarchÒjòVictor AnichebeUttar PradeshÌpínlẹ̀ ÒndóRáràWikiHenri BecquerelInternetChinedu IkediezeLèsóthòXÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáB.L. AfakiryeBostonSantos Acosta28 DecemberÀkójọ àwọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnóIronIvor Agyeman-DuahGiya KancheliDavid JemibewonÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánCarolus LinnaeusBill ClintonSonya Spence.ioBaltimoreỌ́ksíjìnÀwọn Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ NàìjíríàJulian Schwinger4363 SergejIlẹ̀gẹ̀ẹ́sì.blQMayotteIlẹ̀ọbalúayé Rómù Apáìlàoòrùn.geMicrosoft22 February24 AprilÀwọn Bàhámà27 NovemberFáwẹ̀lì Yorùbá23 AprilMilli TarānaFestus KeyamoWeb browser24 OctoberÀjàkáyé-àrùn èrànkòrónà ọdún 2019-2020Baskin-Robbins.soParisiRené DescartesNọ́rwèyDaniel NathanielÀwọn Ìdíje ÒlímpíkìSimidele Adeagbo16 FebruaryAjáLéon BlumJennie KimBẹ̀rmúdàOrílẹ̀-èdè10 October5 DecemberDonald TuskRonald Colman🡆 More