Nnenna Egwuekwe

Nnenna Egwuekwe (bíi ni ọjọ́ kẹji lélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1992) tí orúkọ inagi rẹ jẹ Nenny B je ọmọ Nàìjíríà, ó sì jẹ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún MTV Base Africa.

Nenny B
Nnenna Egwuekwe
Ọjọ́ìbíNnenna Egwuekwe
Oṣù Kẹ̀sán 22, 1992 (1992-09-22) (ọmọ ọdún 31)
Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu University
University of Wollongong
Ìgbà iṣẹ́2007–present
Ọmọ ìlúImo State, Nigeria

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

Wọ́n bí Nnenna sì ìpínlè Èkó. Ó jẹ́ omo ìpínlè Imo ni Naijiria. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Aloysius Primary School ni Abuja fún ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Chukwuemeka Odumegwu Ojukwu University ni ibi tí ó ti gboyè nínú eko èdè gẹ̀ẹ́sì àti Mass Communication. Ó tesiwaju nínú ẹ̀kọ́ rẹ ni University of Wollongong.

Iṣẹ́

Ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ni odun 2007 ni 2007 Kora Awards ni igba ti ó gbé 50 Cent. Ní ọdún 2009, ó sì ṣé pelu Africa Independent Television, AIT, gẹ́gẹ́ bíi olùkọ́ ṣe nínú ètò Matter Arising . Ó kò pá nínú ètò X-Factor West Africa àti Star the Winner is ni ọdún 2014. Ó darapọ̀ mọ́ News Agency of Nigeria (NAN) gẹ́gẹ́ bíi oniroyin. Ní ọdún 2014, ó darapọ̀ mọ́ Hot 98.3 Fm gẹ́gẹ́ bí atọkun fún ètò Daily Drive Time Show àti Battle of The Sexes. Ní ọdún 2017, Radio Magazine fi Nenny B ṣi ojúewé àkọ́kọ́ wọn, wọn si pe ni ìkan laarin awọn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ to tayọ julọ ni Nàìjíríà. Ó ti ṣe atọkun fún àwọn ètò bíi My Big Nigerian Wedding, La Belle Africa, Trace Afrobeat Show, Johnnie Walker Jazz & Whiskey Night, AMVCA After Party, Jamrock, Celeb Living. Ní oṣù kọkànlá ọdún 2017, ní Ilé iṣẹ́ Nkataa fi ṣe aṣojú fún wọn. Láti ọdún 2018 ni ó tí ń sì ṣe fún MTV Base Africa gẹ́gẹ́ bí VJ.

Ẹ̀bùn

Year Event Prize Result Ref
2019 Nigeria Hype Awards TV Personality of the Year Gbàá
Scream All Youth Awards Fast Rising TV Personality Wọ́n pèé
2017 Nigerian Broadcasters Merit Awards Best Radio Show Wọ́n pèé
2016 Exquisite Lady of the Year Female On-Air Personality Wọ́n pèé
2015 Peace Achievers Awards Female On-Air Personality Gbàá
Nigerian Broadcasters Merit Awards Sexiest Female On-Air Personality Wọ́n pèé

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

Nnenna Egwuekwe Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀Nnenna Egwuekwe Iṣẹ́Nnenna Egwuekwe Ẹ̀bùnNnenna Egwuekwe Àwọn Ìtọ́kasíNnenna Egwuekwe

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Olusegun MimikoPúẹ́rtò RíkòKárbọ̀nù22 December23 MaySalawa AbeniIṣẹ́ Àgbẹ̀Owe YorubaISO 15022Auguste BeernaertTenzin Gyatso, 14th Dalai LamaPópù Victor 3kMadridÈdè TàmilJean DujardinIlẹ̀gẹ̀ẹ́sìMariam CoulibalyÌwéCalabar21 JuneVP3EuropeOṣù Kẹ̀sánMwambutsa 4k Bangiriceng ilẹ̀ BùrúndìKalẹdóníà TuntunASCIIOlaitan IbrahimÌbánisọ̀rọ̀-ọ̀ọ́kánPópù Stephen 9kẸ̀bùn NobelỌdúnỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)22 MayÌgèDoha(6065) 1987 OCWaterRita DominicISO 13490NáíráṢáínàPolinésíà.jpIlé-Ifẹ̀31 DecemberIranian rialÀkójọ àwọn orílẹ̀-èdè Europe29 MayUnasPrussiaSinnamon Love1 NovemberUniform Resource Locator8 JulyEukaryoteMichael JordanTiranaGbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdèGírámà Yorùbá🡆 More