Lynn Whitfield: Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Lynn Whitfield (orúkọ ìdílé Butler-Smith; ọjọ́ìbí February 8, 1953) ni òṣeré àti olóòtú ará Amẹ́ríkà.

Whitfield bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìṣeré rẹ̀ ní orí tẹlifísàn àti tíátà, kó tó bẹ̀rẹ̀ sí ní seré nínú fílmù. Ó gba Ẹ̀bùn Primetime Emmy kan, wọ́n sì pè é lórúkọ fún Ẹ̀bùn Golden Globe fún idọ́n rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Josephine Baker nínú eré dírámà tẹlifísàn The Josephine Baker Story (1991).

Lynn Whitfield
Lynn Whitfield: Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Whitfield in 1999
ÌbíLynn Butler-Smith
Oṣù Kejì 8, 1953 (1953-02-08) (ọmọ ọdún 71)
Baton Rouge, Louisiana, U.S.
Iṣẹ́Actress
Awọn ọdún àgbéṣe1981–present
(Àwọn) ìyàwó
Vantile Whitfield (m. 1974–1978)

Brian Gibson (m. 1990–1992)
Àwọn ọmọ1

Whitfield ti kópa nínú àwọn fílmù bíi A Thin Line Between Love and Hate (1996), Gone Fishin' (1997), Eve's Bayou (1997), Stepmom (1998), Head of State (2003), Madea's Family Reunion (2006) àti The Women (2008). Ní 2016, bẹ̀rẹ̀ síní seré bíi Lady Mae Greenleaf nínú dírámà eré tẹlifísàn Oprah Winfrey Network tó únjẹ́ Greenleaf. Whitfield ti gba Ẹ̀bùn NAACP mẹ́je.

Awon Itokasi

Tags:

Josephine BakerUSA

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Òkun Kàríbẹ́ánìAnandi Gopal JoshiAlbuquerqueÌrẹsì Jọ̀lọ́ọ̀fùKhan Abdul Ghaffar KhanDọ́là Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàJean-Paul SartreAIDSOṣù ỌwàràIyánMọ́ṣálásíKánádàNatalie PortmanPétérù 1k ilẹ̀ Rọ́síàElisabeti KejìWikipediaKathmanduHassanal BolkiahGeorge MarshallBeirutÈdè PọtogíDonald TrumpMarylandJürgen Zopp21 LutetiaJames A. GarfieldẸyẹTsílèDenis IstominAkádẹ́mìCreative CommonsÈdè Gẹ̀ẹ́sìPópù Paschal 1k2024Central Intelligence AgencyParagúáìÌmòyeÌṣọ̀kan EuropeJames D. WatsonTehranÀwọn Áràbù27 MarchPópù Jòhánù Páúlù ÈkejìRodney Joseph JohnsonKhafraFriedrich EngelsDọ́là Họ́ng KọngMario BooysenJulie AndrewsHọ́ng KọngÌbálòpọ̀.auSacramento KingsHenry JamesÍndíàTheodosius 1kBẹ̀lárùsỌ̀rànmíyànDallasIPhoneArméníàẸ̀sìn Islam2010LitasÀìsàn ẹ̀jẹ̀ ríruFrench PolynesiaCollectivity of Saint MartinHelmut Kohl🡆 More