King's College

King's College, Lagos jẹ́ ilé ẹ̀kọ́ sẹ́kọ́ndìrì ní Ìpínlẹ̀ Èkó.

Wọ́n dáa síle\̣ ní ọjọ́ ogún oṣù kẹsán ọdún 1909 pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ́ mẹ́wá ní Erékùṣù Èkó, lẹ́gbẹ́ Tafawa Balewa Square. Ìlé ẹ̀kọ́ yìí maa ń gba ọkùnrin nìkan, bíótilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn obìnrin díẹ̀díẹ̀ wà lára wọn (A Level) àwọn akẹ́kọ HSC kí wọ́n tó dá  Queen's College Lagos , sílẹ̀ tí a mọ̀ sí kọ́lẹ́jì obìrin. Báyìí, àwọn akẹ́kọ náà maa ń bá àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn ṣe ìdánwò  West African School-Leaving Certificate àti National Examinations Council.

King's College
Address
Ojúlé kẹta ní Catholic Mission
Ìlú Èkó, Nàìjíríà
Information
Type Ilé è́kọ́ ti ìpínlẹ̀
Motto Spero Lucem
Established 20 Oṣù Kẹ̀sán 1909 (1909-09-20)
Principal Anthony Oluseyi Thomas
Grades JS1–SS3
Gender Àwọn ọkùnrin
Student:teacher ratio 15:1
Slogan Old school, new thinking
Website
King's College
Kings College, Lagos1

Ìtàn nípa rẹ̀

King's College 
Kings College, Lagos3

Ní ọdún  1908, alákóso ètò ẹ̀kọ́ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Henry Rawlingson Carr gba Gómìnà Walter Egerton ní ìyànjú lórí ètò ẹ̀kọ́ ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ìyànjú Carr àti àwọn ìmòràn rẹ̀ ní ó jẹ́ kí wọ́n dá King's College sílẹ̀. Carr jẹ́ kí àwọn London Board of Education ri wípé dídá ilé ìwé yìí sílẹ̀ maa mú ìtẹ̀síwájú bá ètò wọ́n nípa ẹ̀kọ́ ní àwùjọ. Fún ìdí èyí, àwọn olùkọ̀wé kan maa ń pe Henry Carr ní "atukọ̀ King's College". 

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Linda IkejiOlóṣèlúMicrosoftEhoro1151 IthakaÈdè JavaOrílẹ̀ èdè AmericaGúúsù Georgia àti àwọn Erékùṣù Gúúsù SandwichAustrálíàXOṣù Kínní 31Oṣù Kínní 15Nigerian People's PartyDiamond JacksonJulie ChristieSheik Muyideen Àjàní Bello22 DecemberÀrún èrànkòrónà ọdún 2019WolframuOlógbòUSAInternet Relay ChatÀríwá Amẹ́ríkàÈdè YorùbáLiberiaIPv6Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní ilẹ̀ NàìjíríàRichard NixonWiki CommonsAbdullahi Ibrahim GobirOṣù KejìOṣù KẹtaÌṣeọ̀rọ̀àwùjọBobriskyD. O. FagunwaÀkójọ àwọn olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ NàìjíríàVictor Thompson (olórin)Global Positioning SystemISBNEre idarayaLẹ́tà gbẹ̀fẹ̀Àwọn Ẹ̀ka-èdè YorùbáIṣẹ́ Àgbẹ̀30 MarchÌbálòpọ̀Ogun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìWaterWasiu Alabi PasumaDejumo LewisÀdírẹ́ẹ̀sì IPOgun Àgbáyé KìíníAdaptive Multi-Rate WidebandMọ́remí Ájàṣoro🡆 More