Yusuf Kironde Lule (10 April 1912 – 21 January 1985) fìgbà kan jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti orílẹ̀-èdè Uganda, àti òṣìṣẹ́ ìjọba tó sìn gẹ́gẹ́ bí i ààrẹ Uganda kẹrin láàárín oṣù kẹrin àti oṣù kẹfà ọdún.
Yusuf Lule | |
---|---|
4th President of Uganda | |
In office 13 April 1979 – 20 June 1979 | |
Asíwájú | Idi Amin |
Arọ́pò | Godfrey Binaisa |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Yusuf Kironde Lule 10 April 1912 Kampala, Uganda Protectorate |
Aláìsí | 21 January 1985 (aged 72) London, United Kingdom |
Wọ́n bí Yusuf Lule ní 10 Aprilm ọdún 1912 ní Kampala. Ó kàwé ní King's College Budo (1929–34), Makerere University College, Kampala, ní ọdún (1934–36), Fort Hare University ní Alice, South Africa (1936–39) àti ní University of Edinburgh. Ẹlésìn Mùsùlùmí ni tẹ́lẹ̀ kí ó tó gbẹ̀sìn Kìrìsìtẹ́ẹ́nì nígbà tó wà ní King's College Budo.
Ní ọdún 1947, Lule fẹ́ Hannah Namuli Wamala ní ilé-ìjọsìn Kings College Budo, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ bí i olùkọ́, tí arábìrin náà sì jẹ́ olórí àwọn obìnrin.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Yusuf Lule, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.