Ghezo

Ghezo, tí sípẹ́lì rẹ̀ tún jẹ́ Gezo, jẹ́ ọba ilẹ̀ Dahomey, (èyí tó ti di ìlú Benin báyìí) láti ọdụ́n1818 títí wọ 1859.

Ghezo rọ́pò ẹ̀gbọ́n rẹ̀ tí ń jẹ́ Adandozan (tó jọba láti ọdún 1797 títí wọ ọdún 1818) gẹ́gẹ́ bí i ọba látàri ìsọ̀tè tó wáyé pẹ̀lú ìànlọ́wọ́ àwọn olówò ẹrú ilẹ̀ Brasil, ìyẹn Francisco Félix de Sousa. Ó jọba lóri ìlú náà lásìkò tí rúdurùdu gbilẹ̀ ní ilẹ̀ náà, pẹ̀lú ìdíwọ àwọn èbúté lóríṣiríṣi tó ti ọwọ́ àwọn aláwọ̀ funfun wá, láti dẹ́kun Atlantic slave trade.

Ghezo
King of Dahomey

Ghezo
A depiction of King Ghezo in a 1851 publication
Reign 1818–1859
Predecessor Adandozan
Successor Glele
Father Agonglo
Died 1859 (1860)
Ghezo
The Royal flag of Ghezo

Ghezo ló fòpin sí sísan ìṣákọọ́lẹ̀ sí Oyo Empire. It is quite likely that the initial struggle was more violent than this story relates. Lẹ́yìn náà, ó gbógun ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ olówò ẹrú, ní ìbámu láti dẹ́kùn òwò náà. Wọ́n pa Ghezo ní ọdún 1859, ọmọ rè Glele sì jọba.

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

Atlantic slave tradeBeninBrasilDahomey

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Valéry Giscard d'EstaingAkanlo-edeTsílèLiu XiaoboNomsebenzi TsotsobeJoão GoulartÒrùnLudwig van BeethovenAgbonISO 3166-1Steven SpielbergÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunChlodwig, Prince of Hohenlohe-SchillingsfürstÌsọ̀kan Sófìẹ̀tìA. P. J. Abdul KalamSingidaBritish Indian Ocean TerritoryOduduwaOlógbòPakístànAcehYousaf Raza GillaniÈdè GermanyLauryn HillÀjọ tí ó ń mójú tó ońjẹ àti oògùn ti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkàKóstá RikàSeyi ShayLana BanksBarack ObamaHavanaManganisiNiger (country)SARS-CoV-2Ọ̀rànmíyànKinshasaỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Àkójọ àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn agbègbè lóde wọn gẹ́gẹ́ bíi ìpapọ̀ ìtóbiFrançois DuvalierGlasgow2021Ìṣọ̀kan EuropeÈdè PọtogíJames D. WatsonBillie EilishJẹ́mánì NaziÌlúUtahKárbọ̀nùFáwẹ̀lì YorùbáVáclav HavelPópù Gregory 13kÒkunGàbọ̀nBill GatesÌbálòpọ̀Dọ́là Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkàLeonid BrezhnevIléÀwọn ọmọ UkraníàOṣù ỌwàràÈdè KroatíàCynthia McKinneyÌrẹsì Jọ̀lọ́ọ̀fùJosip Broz TitoNikola TeslaJacksonvilleKarachiJohn IsnerAjọfọ̀nàkò Àsìkò Káríayé🡆 More