Manuel Francisco dos Santos (October 28, 1933 – January 20, 1983), to gbajumo pelu oruko alaje Garrincha (Pípè ni Potogí: , little bird), je agbaboolu-elese ni ipo arin egbe otun ati iwaju ara Brazil to ran egbe agbaboolu Brazil lowo lati gba Ife Eye Agbaye ni 1958 ati 1962.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Manuel Francisco dos Santos | ||
Ọjọ́ ìbí | Oṣù Kẹ̀wá 28, 1933 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Pau Grande (RJ), Brazil | ||
Ọjọ́ aláìsí | January 20, 1983 | (ọmọ ọdún 49)||
Ibi ọjọ́aláìsí | Rio de Janeiro, Brazil | ||
Ìga | 1.69 m (5 ft 7 in) | ||
Playing position | Forward | ||
Youth career | |||
1948–1952 | Pau Grande | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps (Gls)† | |
1953–1965 1966 1967 1968 1968–1969 1972 | Botafogo Corinthians Portuguesa Carioca Atlético Junior Flamengo Olaria | 581 (232) 10 (2) 0 (0) 1 (0) 15 (4) 10 (1) | |
National team | |||
1955–1966 | Brazil | 50 (12) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Garrincha, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.