Chuks D General ti órukọ a bisọ rẹ njẹ Chukwuyem Jude Israel jẹ alawada, host, radio presenter ati óṣèrè lọkunrin.
Arakunrin naa gbajumọ lori awọn awada rẹ. Chuks jẹ óludari show ti awada to kó awọn gbajumọ ilẹ naigiria jọ lori idanilaraya. Chuks ni ójẹ alawada to pègèdè julọ ni Abuja. Óṣèrè lọkunrin naa da "Official Couple" silẹ; Èrè oritage naa ṣè afihan Anto Lecky(Ara awọn to kopa ninu idije Big Brother Naija).
Chuks D General ni à bini ọjọ mẹ̀tadinlọgbọn, óṣu February ni Agbor, ipinlẹ Delta. Ni ọjọ kẹrinlèèlógun, óṣu August ni ọdun 2019, Chuks fẹ Ngozi to wa lati Ipinlẹ Anambra.
Chuks lọsi ilè iwè ti Staff Model ni Agbor, Ipinlẹ Delta. Arakunrin naa jadè ni ilè iwè giga ti Ipinlẹ Nasarawa nibi to ti kẹẹkọ lori imọ statistics.
This article uses material from the Wikipedia Yorùbá article Chuks D General, which is released under the Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 license ("CC BY-SA 3.0"); additional terms may apply (view authors). Gbogbo ohun inú ibí yìí wà lábẹ́ CC BY-SA 4.0 àyàfi tí a bá sọ pé kò rí bẹ̀ẹ̀. Images, videos and audio are available under their respective licenses.
®Wikipedia is a registered trademark of the Wiki Foundation, Inc. Wiki Yorùbá (DUHOCTRUNGQUOC.VN) is an independent company and has no affiliation with Wiki Foundation.