Babatunde Omidina: Òṣéré orí ìtàgé

Babatunde Omidina tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́

Babatunde Omidina
Ọjọ́ìbí(1958-08-22)22 Oṣù Kẹjọ 1958
Lagos Island
Aláìsíoṣù Belu (Nòfẹ́mbà) ọdún un 2021
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànBaba Suwe
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • Actor
  • comedian
Ìgbà iṣẹ́1972- 2021
Notable workAṣọ Ìbora

Bàba Sùwé (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1958 jẹ́ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ òṣèré aláwàdà, ipa àwàdà ni ó sìn máa ń kó nínú sinimá tàbí eré orí ìtàgé tí ó bá ti kópa. Eré orí ẹ̀rọ tẹlifíṣọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Ẹ̀rín Kèékèé" ni ìràwọ̀ rẹ̀ tí bú jáde, nínú eré yìí ni orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ yìí tí jẹyọ. Ọjọ́ kejìlélógún, oṣù Belu (Nòfẹ́mbà) ọdún un 2021 ni Bàbá Sùwé dágbére fáyé.


Aáyan rẹ̀ nínú iṣẹ́ tíátà

Babatunde Omidina bẹ̀rẹ̀ eré tíátà lọ́dún 1971. O di ìlúmọ̀ọ́kà nínú eré orí ẹ̀rọ tẹlifíṣọ̀n kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Ẹ̀rín Kèékèé". Kódà, nínú eré aláwàdà yìí ni ó ti gba orúkọ ìnagijẹ rẹ̀, Bàba Sùwé. Lẹ́yìn èyí, ìràwọ̀ rẹ̀ tún búyọ sì í nígbà tí ó kópa nínú àwọn sinimá-àgbéléwò lóríṣiríṣi.

Ààtò díẹ̀ lára àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa

  • Bá ò kú
  • Ojú Olójú
  • Bàbá Londoner
  • Kò tán sí bẹ̀
  • Aṣọ Ìbora
  • Ọ̀bẹ̀ lọmọ
  • elébòlò""

Àwọn Ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

Ẹ̀tọ́-àwòkọNobel PrizeLinda IkejiÍsótòpùNamibiaÀwọn obìnrin alámì pupa.tcÈdè BùlgáríàJosé Miguel de Velasco FrancoRobert B. LaughlinÍsráẹ́lìRáràTaofeek Oladejo ArapajaJennifer LopezMalaysia18946 MassarEmmanuel AmunikeRilwan AkinolúWiki22 October.jpAlastair MackenzieÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáOdunlade AdekolaÒrò àyálò YorùbáISO 31-10PrussiaÀlọ́ÀsìkòAminu Ado BayeroFàdákàolómiÌjàmbá ìtúká ẹ̀búté Bèírùtù ọdún 2020B.L. AfakiryeSudan67085 OppenheimerPọ́rtúgàlIlẹ̀ọba Aṣọ̀kanSókótóOgun Àgbáyé KìíníPoloniumÌlú KuwaitiSukarnoIronAbraham LincolnWikipediaEugenio MontaleJulian SchwingerGlobal Positioning SystemQasem SoleimaniV22 SeptemberLáọ̀sSáúdí ArábíàQOṣù KejeFrancisco Franco.guOhun ìgboroGloria EstefanSílíkọ́nùVladimir PutinIlú-ọba Ọ̀yọ́Àkójọ àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà bíi ìpọ̀síènìyànTurkeyBeirutCharlize TheronÌpínlẹ̀ GeorgiaÀsìá ilẹ̀ UkréìnDavid JemibewonÌgbà EléèédúHerbert MacaulayLos Angeles🡆 More