Aubrey Plaza: Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

 Aubrey Christina Plaza (tí wọ́n bí ni June 26, 1984) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, aláwàdà, àti olùdárí.

Ó kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn April Ludgate lórí NBC sitcom Parks àti Recreation láti 2009 – 2015, àti ìfihàn rẹ̀ nínú jara eré FX Legion (2017 – 2019). Ní ọdún 2022, ó kópa nínú eré àkọ́kọ́ tó jẹ́ apá keji anthology HBO The White Lotus, èyí sì mu gba àmì-ẹ̀yẹ Golden Globe kan.

Aubrey Plaza
Aubrey Plaza: Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Plaza at WonderCon 2019
Ọjọ́ìbíAubrey Christina Plaza
Oṣù Kẹfà 26, 1984 (1984-06-26) (ọmọ ọdún 39)
Wilmington, Delaware, U.S.
Ẹ̀kọ́
  • Ursuline Academy
  • New York University
Iṣẹ́
  • Actress
  • comedian
  • writer
  • producer
Ìgbà iṣẹ́2006–present
Olólùfẹ́
Jeff Baena (m. 2021)

Lẹ́yìn tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré àti aláwàdà lórí ìtàgé Upright Citizens Brigade Theater, ó kópa gẹ́gẹ́ bí èdá-ìtàn kan nínú fíìmù Safety Not Guaranteed ní ọdún (2012). Ó tún ti farahàn nínú fíìmù Mystery Team ní ọdún (2009), Funny People ọdún (2009), Scott Pilgrim vs. World (2010), The To Do List (2013), Life After Beth ọdún (2014), Mike and Dave Need Wedding Dates (2016), Child's Play (2019), àti Happiest Season ọdún (2020). Plaza ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò, ó sì ti ṣàgbéjáde fíìmù bíi Awọn wakati Kekere (2017), Ingrid Goes West (2017).

Àwọn ìtọ́kasí

Tags:

🔥 Trending searches on Wiki Yorùbá:

.glFáwẹ̀lì YorùbáWikipediaÈdè Ìṣèlànà Kọ̀mpútàSeleniumAdolf Otto Reinhold WindausGetaneh KebedeBùrúndìMarcos Pérez JiménezÀktíníọ̀mHaldan Keffer HartlineKareem Abdul-JabbarỌ̀rọ̀ ìṣe5 OctoberMaputoAisha YesufuAustrálásíàKúrùpùJoseph LyonsKurt von SchleicherJodie FosterNọ́mbà átọ̀mùEyvind JohnsonAlan TuringKoreaFiẹtnámNairobiAustrálíàFilniusEré ÒṣùpáGbólóhùn YorùbáMark TwainJ. B. S. HaldaneWhitney HoustonGuatẹmálàSteven SpielbergFranki SwítsàlandìRamón CastillaFọ́tòyíyàYiannis GrivasThierry HenryẸ̀sìn IslamElfrida O. AdeboTurkeyÀmì ọ̀pá àṣẹ ilẹ̀ RùwándàCasablancaTina TurnerIlé ọba àwọn Nẹ́dálándìISO 4217Georges J. F. Köhler2010Orin-ìyìn ÒmìniraYunifásítì KòlúmbíàÀṣà YorùbáManne SiegbahnÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáHafniumCaliforniumProgressive Graphics FileKepu FerdePétérù 1k ilẹ̀ Rọ́síàSheik Muyideen Àjàní BelloBaghdadÈdè Pẹ́rsíàÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣunEukaryoteEswatini🡆 More